Klint da Drunk
Apanilẹ́rìn-ín, òṣèrékùnrin àti olórin ilẹ̀ Nàìjíríà
Afamefuna Klint Igwemba (tí wọ́n bí ní 3 March 1975) tí ó sì ń jẹ́ Klint da Drunk[1] jẹ́ apanilẹ́rin,[2] òṣèrẹ́kùnrin, olórin, ayàwòràń àti oníjó ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà.
Klint da Drunk | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 3 Oṣù Kẹta 1975 Anambra State, Nigeria |
Iṣẹ́ | Comedian, actor, musician, gadget enthusiast and painter |
Ìgbà iṣẹ́ | 1991–present |
Olólùfẹ́ | Lilien Klint-Igwemba |
Àwọn ọmọ | 4 |
Àwọn fíìmù
àtúnṣeTitle | Role | Year |
---|---|---|
Star Girl | Klint | 2021 |
Bond | 2019 | |
Knock Out | 2019 | |
19 Willock Place | Reaper | 2019 |
Price of Deceit | Wande | 2017 |
Brother Jekwu | Ndubisi | 2016 |
Fast Cash | Emeka | 2016 |
Madam 10/10 | Tom-Tom | 2015 |
Ojuju | 2014 | |
Dry | Dr. Mutanga | 2014 |
My House Help | 2007 | |
Lost Kingdom | 2007 | |
Destroyers | 2007 | |
Men on the Run | 2006 | |
Men on the Run 2 | 2006 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "I don't take alcohol due to medical reason, Klint Da Drunk reveals". punchng.com. 9 June 2018. Retrieved 27 April 2018.
- ↑ Ssejjombwe, Isaac. "Klint Da Drunk puts up a good performance at comedy store – Sqoop – Its deep". Sqoop. Retrieved 2019-08-04.