Taxonomy not available for Citrus; please create it automated assistant

Osan koji (Citrus leiocarpa), ti atun pé ni smooth-fruited orange ni ede geesi , bingyul ni Korean, 光橘 (guang ju), 柑 子 (gan zi), ati 日本土柑 (ri ben tu gan) ni Chinese, and コウジ (kōji) ni Japanese, je eya Citrus ti o tan mo Japan.[1] specific epithet (leiocarpa) wa lati Greek leios (= smooth) ati karpon (= fruit). O je taxonomical Citrus aurantium.[2]

Àdàkọ:Speciesbox/hybrid name
Koji orange fruits
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/CitrusCitrus leiocarpa
hort. ex Tanaka (1927)
Forms
  • Citrus leiocarpa f. monoembryota Tanaka
Synonyms

Ipin kiri re

àtúnṣe

Yato si Japan, a máan gbin ni US ati ni apa ile East Asia titi to fi kàn South Korea ati China.[2]

Àpèjúwe

àtúnṣe

Eso yìí jé oblate ni awo, diẹ lo fi ri roboto, o tun tan yóò ,o tun Kere gan pẹlu eso pupo , ati nitori kikere rẹ ati eso pupo yìí ni a ki fi gbin fún ohun ilo eniyan pipo. O Saba maa pọn ni Ọktoba titi wo Novemba,won ti gbin eso yi lati 1900. O ti le je eleso jan. Igi re ní ẹka ni won ba pẹlu ade tó gbọrọ pẹlu trunk kekere . Awo ewe re se green loju dada ati o ri roboto ni awo.[1]

Citrus leiocarpa je eso ti a mo ti o ti ara oríṣi koji (seed parent) ati osan tachibana (pollen parent, Citrus tachibana). Genotype re jọ mo ti komikan ati toukan varieties.[3]

Citrus leiocarpa f. monoembryota, je orisi citrus leiocarpa, ti Chozaburo Tanaka sa àpèjúwe rẹ ri. O ti koko gbagbo wipe o fe fi ara pe osan koji ati wipe asiri Ti tu pe ara koji ati kishu ni o ti jade (pollen parent) and kishu (seed parent).[3] Ni ede Chinese ,a npe ni alled 駿河柑子 (jun he gan zi) ati won tun npe スルガユコウ (suruga yukō) ati 駿河柚柑 (suzuzukan) ni Japanese.

[4]

O tun lewo

àtúnṣe

Awọn Atokasi

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "CRC3147". citrusvariety.ucr.edu. Retrieved 18 January 2021. 
  2. 2.0 2.1 "Citrus leiocarpa hort. ex Tanaka". www.gbif.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 18 January 2021. 
  3. 3.0 3.1 Shimizu, Tokurou; Kitajima, Akira; Nonaka, Keisuke; Yoshioka, Terutaka; Ohta, Satoshi; Goto, Shingo; Toyoda, Atsushi; Fujiyama, Asao et al. (30 November 2016). "Hybrid Origins of Citrus Varieties Inferred from DNA Marker Analysis of Nuclear and Organelle Genomes". PLOS ONE 11 (11): e0166969. Bibcode 2016PLoSO..1166969S. doi:10.1371/journal.pone.0166969. PMC 5130255. PMID 27902727. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=5130255. 
  4. "M.M.P.N.D. - Sorting Citrus names part1". www.plantnames.unimelb.edu.au. Retrieved 12 February 2021. 

Àdàkọ:Citrus