Kola Oyewo
Kola Oyewo (bìi ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọn Oṣù kẹta 1946) jẹ́ òṣèré àti olùkọ́ ọmọ orìlé èdè Nàìjírìà
Kola Oyewo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kẹta 1946 |
Orílẹ̀-èdè | orìlé èdè Nàìjírìà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | orìlé èdè Nàìjírìà |
Iṣẹ́ |
|
Gbajúmọ̀ fún | The Gods Are Not To Blame and Sango (1997) |
Ìgbà èwe
àtúnṣeA bìi ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọn Oṣù kẹta 1946 ní ìlú Ọ̀bà ilé ti ìlú Ọ̀ṣun gúúsù-wọ̀orùn Nàìjírìà.[1]
Ètò ẹ̀kọ́
àtúnṣeÓ lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ Yunifásitì níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí nínu ìmo eré ìtàgé kí ó tó gba oyè kínín (B. A) nínu ìmọ tíátà ní Yunifásitì kan náà ní ọduń 1995. Ó tẹ̀síwájú nínu ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Yunifásitì ti ìlú Ìbàdàn níbi tí ó ti gba oyè kejì (M. A) àti ìkẹta (Ph. D) ní ìmọ eré ìtàgé.
Iṣẹ́
àtúnṣeÓ bẹ̀ẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní odún 1964 lẹ́yìn tí ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré Oyin Adéjọbí. Ipa tí ó kọ́kọ́ kó ni Adéjàre nínú eré Orogún Adédigba, èyí tí ó jẹ́ ìgbésí ayé Oyin Adéjọbí.[2] Lẹ́yìn tí ó lo ọdún mẹ́ẹ́san pẹ̀lú Oyin Adéjọbí, ó darapọ̀ mọ́ egbé tíátà Yunifásitì ilé ifẹ̀ níbi tí ó tí bá olóyè Olá Rótìmí, tí ó jẹ́ òṣèré àti olùkọ́ ṣisẹ́. Wọ́n mọ Kola Oyewo sí Ọdẹ́ wálé, ipa tí ó kó nínu The Gods Are not to Blame, eré tí Olá Rótìmí kọ.
Ní odún 1996, ó darapọ̀ mọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ Yunifásitì bí olúkọ́, ó sì dí àgbà olùkọ́ kí ó tó fẹ̀hìntí ní Oṣù kesań 2011.[3] Lẹ́yìn tí ó fẹ̀hìntì, ó darapọ̀ mọ́ Yunifásítì Reedemers, níbi tí ó ti jẹ́ olórí olùkó ẹ̀ka eré ṣíṣe[4]
In 1996, he joined the services of Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ where he rose to the rank of a senior lecturer before he retired in September 2011.[5] After his retirement from Obafemi Awolowo University, he joined the services of Redeemer's University, where he currently serves as head of the department of dramatic art.[6]
Àwọn eré
àtúnṣe- Sango (1997)
- Super story (episode 1)
- The Gods Are Not To Blame
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "I Dread Polygamy - Kola Oyewo". nigeriafilms.com. Retrieved 16 February 2015.
- ↑ http://tribune.com.ng/news2013/index.php/en/news/item/298-my-second-son-and-i-graduated-same-day-—kola-oyewo.html
- ↑ "My father has no social life — Kola Oyewo’s son" Archived 2015-02-15 at the Wayback Machine..
- ↑ "Redeemers University - P.M. NEWS Nigeria". pmnewsnigeria.com.
- ↑ "My father has no social life — Kola Oyewo’s son" Archived 2015-02-15 at the Wayback Machine..
- ↑ "Redeemers University - P.M. NEWS Nigeria". pmnewsnigeria.com.