Kolkhoznitsa melon
Kolkhoznitsa melon, je eso ti a tun mo sí egusi ti awọn akojọpọ agbe obirin, o je eso egusi ninu ẹyà Cucumis ti o tan mo Russia ,ti a tun fi mo awon ara ile Amerika ni ọdún 1993.[1]
Àpèjúwe
àtúnṣeA koko gbìn ni ọdún 1930s nipasẹ Russian gardener , fun akoko kekere kan. Igba ti o ya lotan dé ile Europe bi Ukraine,ki o to wa dé ile Amerika .[2] Rindi rẹ Tirin ati wipe o ni awo golden orange,ẹran ara rè sí funfun ati dense.O ri roboto sí oblong ni irisi. Oorun rẹ dùn àti pé o to 3 pounds (1.4 kilograms). Àwọn irúgbìn yìí je eso ti o tutu ti o sì lè pẹlu,o dé ndagba ni averagi egusi meta ni asiko kan[1]
Orúkọ
àtúnṣeA so Kolkhoznitsa melon ni orúkọ yìí nipa ajokopo agbe ni ile Soviet Union ti a mo sí kolkhoz.
Wiwa re
àtúnṣeEso irúgbìn yìí wa jakejado ayelujara.
Awọn Atokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "25 KOLKHOZNITSA MELON Collective Farm Women Cucumis Melo Russian Fruit Seeds". seedvilleusa.com. Archived from the original on 28 February 2021. Retrieved 19 January 2021.
- ↑ "Collective Farm Woman Melon - (Cucumis melo var. inodorus) | Farm women, Melon, Food garden". Pinterest (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 24 April 2021.