The Komadugu Beôeô River tábì odó Misau jẹ́ odò́ nì ílù Chad Basin nì árìwà Nigeria tì parapó mọ Yobe River nì Damasak, nì Mobbar agbègbè Ìjọba Borno State . [1] Ó selẹ̀ ní àríwá Bauchi . [2]

Agbegbe mimu ti Odò Yobe

Gẹ́gẹ́bí ìjábọ̀ 2011 ńipasẹ̀ International Union fún Conservation of Nature, ṣíṣàn omi odò ýi kò dé Yóbè mọ́. [3]

A ṣe àwárí ọkọ̀ ojú omi Dufuna tí o jẹ́ ọdún 8,500 l'àkókò ìwakúsá nítòsí odò yí ní ọdún 1987 ní Ìjọba Ìpíilẹ̀ Fune. [4]

Awọn itọkasi

àtúnṣe

 

  1. Mortimore, Michael. Adapting to Drought: Farmers, Famines, and Desertification in West Africa, p. 244 (1989)(note 3 notes that the Komadugu Gana joins the Yobe at Damasak)
  2. Oyebande, Lekan. Streamflow regime change and the ecological response in the Lake Chad basin in Nigeria, in Hydro-ecology: Linking Hydrology and Aquatic Ecology, p. 101, 104 (2001) (Acreman, M.C., ed.)
  3. Komadugu Yobe Basin,upstream of Lake Chad, Nigeria, WANI Case Study Archived 2012-05-13 at the Wayback Machine., IUCN, Report 2011-009
  4. (24 May 1998). 6,000-Year-Old Canoe To Be Removed, Associated Press