Konstantinos Demertzis (Gíríkì: Κωνσταντίνος Δεμερτζής; 1876, Athens – 1936, Athens) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Greece. Ó jẹ́ alákòóso àgbà  lati Oṣù kọkànlạ ọdún 1936 sí Oṣù kẹrin ọdún 1936. Demertzis di olóògbé nípasẹ̀ ààrùn ọkàn ní Ọjọ́ kẹtàlá Oṣù kẹrin ọdún 1936.

Konstantinos Demertzis

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe