Kosoko ku ni ọdún (1872)[1] jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ oyè ologun kutere ti ìlú Èkó tí ó kọ̀wé f'ipò sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba Èkó láàárín ọdún 1845 sí 1855.[2][3] Biyemi, Adebajo, Matimoju, Adeniyi, Isiyemi, Igbalu, Oresanya, àti Idewu-Ojular Bàbá a rẹ̀ ni Ọba Osinlokun àwọn ẹbí rẹ̀ ni Idewu Ojulari (tí ó jẹ́ ọba láàárín ọdún 1834/35),[4] Os Olufunmi, Odunsi, Ladega, Ogunbambi, Akinsanya, Ogunjobi, Akimosa, Ibiyemi, Adebajo, Matimoju, Adéníyì, Isiyemi, Igbalu, Oresanya, àti Idewu-Ojulari.[5]

Kosoko
Oba of Lagos
1845–1851
Akitoye
Akitoye
Father Osinlokun
Born Lagos
Died 1872
Lagos
Burial Iga Ereko, Lagos

Àsìkò rẹ̀ lórí oyè

àtúnṣe

Ìgbà kosoko lórí oyè Ọba Èkó ní ọdún 1845 jẹ́ èyí tí ó kún fún àwọn oríṣiríṣi ìṣẹ̀lẹ̀ mánigbàgbé.[6]

Aáwọ̀ láàárin Osinlokun àti àwọn Adelé

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Kosoko". LitCaf (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-01-19. Retrieved 2022-01-27. 
  2. O, OSHIN SHERIFF (2018-04-18). "Oba Kosoko: His Military Strength And The Struggle For Lagos Kingship". Medium (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-06. 
  3. Shin, Eun-Ja (2005-09-30). "Measuring Impact of Scholarly Digital Archives : Analyses on Citation Indicators of PMC Journals". Journal of Information Management 36 (3): 51–70. doi:10.1633/jim.2005.36.3.051. ISSN 0254-3621. 
  4. Mann, Kristin (23 April 2024). Slavery and the Birth of an African City: Lagos, 1760–1900. Indiana University Press, 2007. p. 45. ISBN 9780253348845. 
  5. Mann, Kristin (23 April 2024). Slavery and the Birth of an African City: Lagos, 1760–1900. Indiana University Press, 2007. p. 45. ISBN 9780253348845. 
  6. Jimoh, Oluwasegun Mufutau (2019-07-12), Goerg, Odile; Martineau, Jean-Luc; Nativel, Didier, eds., "Independence in Epe (Nigeria): political divisions leading to a dual celebration", Les indépendances en Afrique : L'évènement et ses mémoires, 1957/1960-2010, Histoire, Rennes: Presses universitaires de Rennes, pp. 273–292, ISBN 978-2-7535-6947-8, retrieved 2022-01-28