Krystal Okeke
Krystal Okeke jẹ́ oníróyìn àti mọ́dẹ́lì ọmọ Nàìjíríà.[1][2] Òun ni olùdásílè ẹgbẹ́ America Kids Multicultural Organisation àti Miss and Mrs America Nation beauty pageant.[3][4]
Krystal Okeke | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Chicago, Illinois, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Governors State University Prairie State College |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2012–present |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bíi Krystal sì Chicago, Illinois ni orílẹ̀ èdè USA. Ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Taraba. Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Taraba, ìyá rẹ si jẹ́ ọmọ Anambra.[5] Ó lo ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ aiyé rẹ ni Kaduna níbi tí ó gbé fún ọdún mẹ́rìndínlógún kí ó tó padà sí USA.[6] Ní ọdún 2017, ó gboyè nínú mass communication láti Praire State college kí ó tó padà tún wà gboyè nínú ìròyìn láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Governors State University.[7]
Iṣẹ́
àtúnṣeKrystal nífẹ̀ẹ́ sì iṣẹ́ mọ́dẹ́lì, ó sì ti bẹ̀rẹ̀ láti bíi ọmọ ọdún márùn-ún. Ní ọdún 2012, nígbà tí ó si wà ní Nàìjíríà ni ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ mọ́dẹ́lì gẹ́gẹ́ bíi iṣẹ́. Ní ọdún 2016, ó gboyè Miss Illinois USA, leyin ti o ti gbìyànjú láti gba ni ẹ mẹta tẹ́lẹ̀. Ó ṣe aṣojú fún ìpínlè Illinois ni Miss USA Universal ni ọdún 2016, ó sì gbé ipò kẹta.[8] Ní ọdún 2017, ó dá America Kids Multicultural World Organization ati Miss America Nation beauty pageant sílẹ̀.[9][10] Ní oṣù Kẹ̀wá ọdún 2019, ó gbà ẹ̀bùn gẹ́gẹ́ bí asoju fún àwọn Ọlọpa ní Nàìjíríà.[11]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Nda-Isaiah, Solomon (30 March 2016). "Nigeria: Miss Illinois Shows Love to Less-Privileged On Easter Day". Archived from the original on 30 March 2016. https://web.archive.org/web/20160330155124/https://allafrica.com/stories/201603300115.html. Retrieved 13 January 2020.
- ↑ Nda-Isaiah, Solomon (8 January 2020). "Kaduna State Police Wives Association Empower Widows". Leadership Newspaper. Retrieved 13 January 2020.
- ↑ "Chicago Multicultural Kids Fashion Show preview". WLS-TV. 17 June 2018. Retrieved 13 January 2020.
- ↑ "Miss & Mrs America Nation 2019". Pageant Planet. Retrieved 15 January 2020.
- ↑ "Nigerian Born US Beauty Queen Krystal Okeke Dazzles In Fulani Attire Photo shoot After Abuja Visit". Modern Ghana. 28 June 2017. Retrieved 13 January 2020.
- ↑ Kopycinski, Gary (2 May 2016). "Sitting Down With Krystal Okeke, Park Forest's Own Ms. Illinois USA Universal 2016". eNews Park Forest. Retrieved 13 January 2020.
- ↑ Jo, Daniel (26 May 2017). "Krystal Okeke Bags World Class Beauty Queen Award (Photos)". Information Nigeria. Retrieved 13 January 2020.
- ↑ "Nigerian Beauty, Krystal Okeke, Mz Illinois Dazzles At Ms USA Universal Contest, Named State Ambassador". The Nigerian Voice. 12 August 2016. Retrieved 13 January 2020.
- ↑ "150 Kids Showcased Fashion At Chicago Halloween And MulticulturalShow Hosted By Krystal Okeke". Modern Ghana. 13 January 2020. Retrieved 13 January 2020.
- ↑ "2019 Miss and Mrs America Nation; and Kids Multicultural Runway". Briyanakelly.com. 15 April 2019. Archived from the original on 13 January 2020. Retrieved 13 January 2020.
- ↑ "American Born Nigerian Beauty Queen Hosts Nigeria Top Police Commissioners In Chicago, Receives Police Ambassadorial Medal Of Honour (Photos)". Igbere TV. 30 October 2019. Retrieved 13 January 2020.