Kunle Ajibade

Oníwé-Ìròyín

Kunle Ajibade (tí wọ́n bí ní 28 May 1958) jẹ́ akoroyin, olóòtú àti òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria. Ní ọdún 1995, pẹ̀lú Olusegun Obasanjo, àti àwọn oníròyìn mẹ́ta mìíràn, ni wọ́n fi ẹ̀sùn ọ̀tẹ̀ kàn.[1] [2] Ní ọdún 1998/1999, ó di ọmọ ẹgbẹ́ Feuchtwanger ní Villa Aurora ní Los Angeles. [3]

Kunle Ajibade
Ọjọ́ìbí(1958-05-28)28 Oṣù Kàrún 1958
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaObafemi Awolowo University
Iṣẹ́Journalist, editor, writer

Ètò-ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ajíbádé gboyèẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Masters nínú ìmọ̀ Literature-In-English láti Obafemi Awolowo University. Ó ti ṣiṣẹ́ bíi akọ̀ròyìn àgbà ní The African Concord, aṣèrànwọ́ olóòtú ní The African Guardian, àti bí olóòtú àgbà ní TheNEWS àti PM News.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe