Kyenvu
Kyenvu jẹ fiimu ranpe 2018 Ugandan, ti Kemiyondo Coutinho je eni to kọ tosi tun daari. Kemiyondo Coutinho fun ra e pelu Michael Wawuyo Jr. kopa osere iwaju ti Rehema Nanfuka si gbewon leeyin. Joel Okuyo Atiku, Alex Bwanika, Bash Luks ati awon miira na kopa ninu ere na. Ere na akoko ti Kemiyondo Coutinho ma gbe jaade ti osi tun daari, osi gba ami eye ti ere ranpe toni alaaye to daaju ni Pan African Film Festival.[1][2]
Nipa Itan
àtúnṣeỌmọbirin kan alawo ofeefee ti o ṣẹṣẹ pada wa gba owo gba maabinu lowo ikan ninu awon ero-oko tojr okunrin nigbati oludaari ero oko na gbiyanju laati yaanje. Arakunrin na setan lati san owo oko re, oun to tele si ni ere etan ati iyanje laarin omobirin ati arakunrin na.
Ṣiṣejade
àtúnṣeKyenvu ṣeto sinu takisi kan, oko akero merinla kan. Gege bi Kemiyondo Coutinho ti so, won ma fi awọn ọmọbirin sẹgan fun imura wọn ni awọn takisi, awọn popona ati nibikibi. O ko Kyenvu ni ọdun 2014 nigbati ofi “Ma wowokuwo” fidi mule ni Uganda. Kyenvu jẹ ọrọ Luganda ti o tumọ si awọ ofeefee, eyiti ti won lo bi apẹrẹ ninu fiimu naa ati ni gbogbo gberiko Uganda lati ṣe apejuwe ọmọbirin tiko ponju ti kosi dudu ju. Fiimu naa nlo awọ lati ṣe afihan awọn iṣoro ti awọn ọmọbirin to lowo to yaato ma n koju. Awọn ọmọbirin alawo yii ma n se jamba orisirisi akolu bi asodun ewa ara obirin, ifipabanilopo, ati bẹbẹ lọ. Peter Mukiibi ni o ṣatunkọ fiimu naa, Isaac Ekuka ni oludari fọtoyiya ati orin nipasẹ Moses Bwayo.[3][4][5]
Awọn ẹbun | |||
---|---|---|---|
Odun | Eye | Ẹka | Abajade |
2018 | Pan African Film Festival (awọn ẹbun PAFF) | Gbàá[6] | |
Uganda Film Festival Awards | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé |
Awọn itọkasi
àtúnṣe- "Kemiyondo’s “Kyenvu” wins Best Short Award at Pan African Film Festival 2018 in Los Angeles". Mbu. Retrieved 2 June 2018.
- "What you need to know about Kyenvu". Daily Monitor. Retrieved 2 June 2018.
- "'Kyenvu' Is the Short Film Challenging Uganda’s Controversial Mini-Skirt Bill". Okay Africa. Retrieved 2 June 2018.
- "Pan African Film Festival - Kyenvu". We Are Moving Stories. Archived from the original on 27 February 2018. Retrieved 2 June 2018.
- "Kemiyondo’s star rises with Kyenvu". Nilepost. Retrieved 2 June 2018.
- ↑ "Kemiyondo’s “Kyenvu” wins Best Short Award at Pan African Film Festival 2018 in Los Angeles". Mbu. Retrieved 2 June 2018.
- ↑ "What you need to know about Kyenvu". Daily Monitor. Retrieved 2 June 2018.
- ↑ "'Kyenvu' Is the Short Film Challenging Uganda’s Controversial Mini-Skirt Bill". Okay Africa. Retrieved 2 June 2018.
- ↑ "Pan African Film Festival - Kyenvu". We Are Moving Stories. Archived from the original on 27 February 2018. Retrieved 2 June 2018.
- ↑ "Kemiyondo’s star rises with Kyenvu". Nilepost. Retrieved 2 June 2018.
- ↑ "Pan African Film Festival: More reviews and PAFF awards". Peoples World. Retrieved 3 June 2018.