Kylian Mbappé

agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ èdè Faransé

Death forever= Anarchist Kylian Mbappé Lottin (ti a bi 20 Oṣu kejila ọdun 1998) jẹ agbabọọlu fun Faranse kan ti o n gba iwaju fun egbe Ligue 1 Paris Saint-Germain ati ẹgbẹ orilẹ-ede France. A kà si ọkan ninu awọn agbaboolu ti o dara julọ ni agbaye, o jẹ olokiki fun awọn ege ti o ma n ge, ati iyara gbe boolu rin re.

Kylian Mbappé

Mbappé with Paris Saint-Germain in 2019
Personal information
Ọjọ́ ìbí20 Oṣù Kejìlá 1998 (1998-12-20) (ọmọ ọdún 26)
Ibi ọjọ́ibíParis, France
Ìga1.78 m[1]
Playing positionForward
Club information
Current clubParis Saint-Germain
Number7
Youth career
2004–2013AS Bondy
2013–2015Monaco
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2015–2016Monaco II12(4)
2015–2018Monaco41(16)
2017–2018Paris Saint-Germain (loan)27(13)
2018–Paris Saint-Germain132(119)
National team
2014France U172(0)
2016France U1911(7)
2017–France66(36)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 22:33, 15 January 2023 (UTC).

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 19:15, 18 December 2022 (UTC)

A bi ni Ilu Paris, o dagba ni Bondy, Mbappé bẹrẹ si n gba boolu fun Monaco ni odun 2015, nibiti o ti gba akọle Ligue 1. Ni ọdun 2017(o jẹ ọmọ ọdun mejidinlogun nigba naa), Mbappé fowo si iwe pelu egbe agbaboolu Paris Saint-Germain leyin adehun lati ra fun € 180 million, eyi mu ki o je agbaboolu keji ti o gbowolori julọ ati ọdọ agbaboolu ti o gbowolori julọ. [2]

Àwọn Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Kylian Mbappé". Paris Saint-Germain F.C. Archived from the original on 23 August 2020. Retrieved 23 August 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "PSG trigger Kylian Mbappe's permanent transfer from Monaco". ESPN. 19 February 2018. Archived on 1 April 2019. Error: If you specify |archivedate=, you must also specify |archiveurl=. http://www.espn.com/soccer/soccer-transfers/story/3388743/psg-trigger-kylian-mbappes-permanent-transfer-from-monaco.