Labid Khalifa tí a bí ní ọjọ́ àkọ́kọ́, óṣu kìíní ọdún 1955 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá tó jẹ́ defender fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Morocco.[1]

Labid Khalifa
Personal information
Ọjọ́ ìbí1 Oṣù Kínní 1955 (1955-01-01) (ọmọ ọdún 69)
Ibi ọjọ́ibíMorocco
Ìga1.68 m (5 ft 6 in)
Playing positionDefender (association football)
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
KAC Kenitra
National team
Morocco national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Àṣèyọri

àtúnṣe

Labid ṣerè fun KAC Kenitra, arákùnrin náà ṣerè fún orílẹ̀-èdè Morocco ní Cup FIFA Agbayè ti ọdún 1986.[2][3][4][5]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe