Ladipo Market
Ladipo market ti a tun mo si Ladipo Auto Spare Parts Market je oja to wa ni agbegbe ijoba ibile Mushin ni ipinle Eko . [1] Ní bi ijó méta seyin, Ọjà Ladipo ti jẹ́ ibi tí àwon tí wón ti ún se ìpolongo òṣèlú nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn tó wà nínú ọjà náà. [2]
Oja naa wa ni Ladipo Street, Papa Ajao, Mushin, Lagos. Wón fún ojà yen loruko náà nitori pé o wà ní Ladipo Street. Oja Ladipo wa ni agbegbe Akinwunmi Lane, Ladipo Street, Papa Ajao, Mushin, ìpínlè Eko. Ojà náà ní or is I risk ònà abawole tí o jáde sí orisirisi ibi nií ìpínlè Eko. Òun ni ọja ti o tobi julọ fun rira awọn ẹya ọkọ ni gbogbo Afirika. O jẹ ibi tí wón ti ún ta èyà tokunbo àti èyà moto tuntun ni Nigeria, àwon ènìyàn si ma ún wá lati Ghana, Ivory Coast, ati awọn orilẹ-ede oriṣiriṣi ni Afirika.
Wiwo apá kan ibè
àtúnṣeNitori aini awọn ọna ti o dara ati aaye TiVo to ni ojà náà, ijọba ipinlẹ Eko ni 30 June, ọdun 2015 da apakan ojà náà wo èyí sì fa wahala púpò laarin ọja naa.
Wo eyi naa
àtúnṣe- Akojọ ti awọn ọja ni Lagos
- Oju opo wẹẹbu ojà náà: https://www.ladipoautomarket.com.ng
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ "Ladipo Market boils as thugs attack traders". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. February 23, 2011. Archived from the original on July 9, 2015. Retrieved September 12, 2022. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Fashola visits Ladipo market, seeks traders' support for Ambode - Premium Times Nigeria". Premium Times Nigeria. February 10, 2015. Archived from the original on July 7, 2015. Retrieved September 12, 2022. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)