Lagos Lagoon jẹ́ omi ọ̀sà[1] tí ó bá Ìlú Èkó jorúkọ. Orúkọ yìí jẹ́ orúkọ Àgùdà tí ó túnmọ̀ sí "Omi ńlá" ní Èdè Àgùda, nítorí èyì "Lagos Lagoon" jẹ́ àpẹrẹ orúkọ ìbálú jórúkọ.

Lagos Lagoon
Location Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Coordinates 6°30′06″N 3°31′21″E / 6.5015814°N 3.5224915°E / 6.5015814; 3.5224915Coordinates: 6°30′06″N 3°31′21″E / 6.5015814°N 3.5224915°E / 6.5015814; 3.5224915
Lake type lagoon
Basin countries Nàìjíríà
Max. length 50 km
Max. width 13 km
Surface area 6,354.7 km²
Surface elevation 0 m
Islands Lagos Island, Victoria Island
Settlements Èkó
Lagoon ìpinlẹ̀ Èkó

Ìrísí rẹ̀

àtúnṣe

Gígùn ọ̀sà yìí ju àádọ́ta kìlómítà lọ, ó jìnà sí òkun pẹ̀lú fífè méjì sí márún, tí ó sì ní irà lẹ́bá etí ọ̀sà. Fífẹ̀ rẹ̀ tó bíi 6,354.7 km².[2] Ọ̀sà yìí tòrò níwọ̀nba, tí àwọn ọkọ̀ ojú omi nla tó ń gba ojú òkun kìí dàárú.

Ọ̀sà yìí jápọ̀ mọ́ Odò Ògùn àti Odò Ọsun.


Àwọn àwòrán rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn Itokasi

àtúnṣe
  1. R. H. Hughes (1992). A Directory of African Wetlands. IUCN. pp. 411–. ISBN 978-2-88032-949-5. http://books.google.com/books?id=VLjafeXa3gMC&pg=PA411. 
  2. Lagos Lagoon Coastal Profile: Information Database For Planning Theory, by Obafemi McArthur Okusipe, Department of Urban and Regional Planning, University of Lagos - Accessed September 22, 2008