LAKA

ÀÀYÈ WỌN

Grúsù ìls̀ oòrùn chad ni wọ́n wà

IYÈ WỌN

Ẹgbèrún lọ́nà ọgóruǹún

ÈDÈ WỌN

Lake àti Mbonu (Niger-Congo) ni wọ́n ń ṣo

ALÁBÀÁGBÉ WỌN

Sára, Èèyan Cameroon àti Fúlaní ni múlé tí wọ́n

ITAN WỌN

Àríwá ìlà oòruń oko chad ni wọ́n ti ṣẹ. Ijọba ńlá tí Fúlàní ló wọn dèbi wọ́n wà yìí. Èdè àti aṣa wọn àti ti Cameroon tó jẹ́ bákan náà.

ÈTÒ ÌṢÈLÚ WỌN

Eto ìṣè ijọba abúlè wọ́n jẹ́ ti ẹlẹ́bí baba. Olórí febí wọn gbọ́dọ́ le tan orírun wọn sí ọ̀dọ̀ baba ńlá Laka. Olórí yìí ló sì ń ṣe ìfilọ̀ ètò àgbẹ̀

ỌRỌ̀ AJÉ

Owú ni wọ́n fi ń sọwó sókè òkun. Agbàdo, bàbà àti ohun ẹnu ń jẹ ló pọ̀ lọ́dọ̀ wọn Àsíkò òjọ nikan ni wọn le ṣe ògbìn nǹkan wòńyi.

IṢẸ́ ỌNÀ WỌN

Àwọn ló ń ṣọnà sí ara. Èyí ni wọn ń lò nígbà aápọ̀n tabi obitan

Ẹ̀SÍN WỌN

Ẹbi wọn sì ń pèṣè fún àwon òkú ọ̀run wọn lójoojúmọ́.

LAKA Orúkọ èdè yìí ni a mọ̀ sí Lákà; tí orúkọ rẹ̀ mìíràn a tún máa jẹ́ Kabba Laka. Èdè adugbo wọn ni a mọ̀ sí Bemour Goula, Mang Maingao pai. Aarin gbungbun ilẹ Chad ni wọn ti n sọ o; wọ́n sì jẹ́ ibatan pẹ̀lú Nilo-Saharan. LAP ni ami tí wọn kọ́kọ́ ń lò dípò èdè Ganda. Àwọn àmì ẹka wọn la mọ̀ sí N S B B A C B A..