Lamberto Dini

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Italy

Lamberto Dini jẹ́ Alákòso Àgbà ilẹ̀ Italia tẹ́lẹ̀. A bi ni ọjọ́ kìnní oṣù kẹta ọdún 1931. Òun ni Mínísítà Àgbà kọkàn-lé-laadọta fún orílẹ̀-èdè Italia laarin ọdụn 1995 sí 1996 àti Mínísítà fún ilẹ̀ òkèèrè láti ọdún 1996 si 2001.

Lamberto Dini
Lamberto dini pl.jpg

Ìbèrè ìgbésí ayéÀtúnṣe

Lẹ́yìn ti o k'ẹko ninu ìmò ètò ìṣúná owò

ItokasiÀtúnṣe