Lamide Akintobi
Lamidi Akintobi jẹ́ oníróyìn àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni Nàìjíríà. Ó sì ṣe gẹ́gẹ́ bíi atọkun ìròyìn lórí Channels TV.[1] Ó ti si ṣé pelu Zainab Balogun àti Ebuka Obi-Uchendu gẹ́gẹ́ bíi atọkun fún ètò The Spot lórí Ebonylife TV.
Lamide Akintobi | |
---|---|
Lamide Akintobi | |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | journalist, television personality |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006-present |
Ìbéèrè pẹpẹ aiyé àti ẹ̀kọ́ rẹ.
àtúnṣeAkintobi jẹ́ ọmọ Abẹ́òkúta ni ìpínlè Ogun.[2] Ó gboyè B. A nínú ìmò agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati èdè Spanish láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Volunteer State Community College ni Tennesse àti Texas A&M University - Commerce.[3] Ó gboyè master's rẹ nínú International journalism láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí City University ni London.[4] Lamide di ọmọ ẹgbẹ́ Delta Sigma Theta ni ọdún 2004.[5]
Iṣẹ́
àtúnṣeAkintobi ṣi ṣé gẹ́gẹ́ bíi atọkun ètò ìròyìn lórí Channels TV.[1] Ó si ṣé pelu Zainab Balogun àti Ebuka Obi-Uchendu gẹ́gẹ́ bíi atọkun fún ètò The Spot lórí Ebonylife TV, ó sì gbé ère El Now jáde.[6][7]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Lamide Akintobi Lands at TVC". TheNet. January 18, 2012. Archived from the original on 7 November 2017. https://web.archive.org/web/20171107023946/http://www.thenet.ng/2012/01/lamide-akintobi-lands-at-tvc/. Retrieved 8 October 2016.
- ↑ "Secret lives of Baba segis wives author Lola Shoneyin & the Trio discuss attitudes & their altitudes". Ebonylife Television – via YouTube.
- ↑ "The 'It-Guys' of Ebonylife TV". EbonyLife TV. Archived from the original on 2017-09-03. Retrieved 2020-05-20.
- ↑ "5 things you didn't know about Lamide Akintobi". Loudestgist. 30 June 2016. Archived from the original on 9 October 2016. Retrieved 8 October 2016.
- ↑ "Chats with Nigerian-based presenter and producer, Lamide Akintobi". Thea1tv.com. 8 October 2015. Archived from the original on 12 October 2016. Retrieved 8 October 2016.
- ↑ https://www.lamidelive.com/about-me#bio
- ↑ "AY Makun, Dolapo Oni, Bolanle Olukanni, Runtown, Lamide Akintobi are a year older today". Pulse. Retrieved 8 October 2016.