Lana Marks
Lana J. Marks (ọjọ́ ìbí rẹ̀ jẹ́ ọjọ́ kéjìlélógún oṣù kọkànlá ọdún 1953) tí ó jẹ́ Ọmọ orílè èdè South Africa tí wọ́n bí sì Ìlú Amẹ́ríkà jẹ́ Ọ̀gá àgbà tí ó dá Ilé Iṣẹ́ Fún aṣọ àti Ẹ̀ṣọ́ Oge ṣíṣe ìgbàlódé. Ó jẹ́ Ọ̀kan lára àwọn Aṣojú Amẹ́ríkà sí Ìlú South africa tí ó sì ṣíṣe náà láti 2020 títí di òní yìí [1] ọdún 2021.
Lana Marks | |
---|---|
United States Ambassador to South Africa | |
In office January 28, 2020 – January 20, 2021 | |
Ààrẹ | Donald Trump |
Asíwájú | Patrick Gaspard |
Arọ́pò | Reuben Brigety |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Lana Bank 18 Oṣù Kọkànlá 1953 East London, South Africa |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Republican |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Neville Marks (m. 1976) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Ìgbé ayé àti ètò ẹ̀kọ
àtúnṣeWọ́n bí Lana Banks sí Ìlú East London ni apá ìlà Òòrùn ni Cape Town ni orílẹ̀ èdè South Africa. Bába rẹ̀, Alec Bank tí ó ṣí lò láti Litvaks ni Lithuania láti kékeré, jẹ́ gba jú-gbajà nínú ìṣẹ́ gbígbé Ohun Ìní jáde bí ilé àti pé Ó jẹ́ Olórí rì ni àwùjọ Júù.[2]Ó lọ sí ilé ìwé ṣẹ́kọ́ndírì Clarendon tí ó jẹ́ ilé ìwé fún àwọn obìnrin ni East London tí wọ́n sì ń sọ èdè Xhosa àti Afrika. [3] Marks jẹ́ onífée agbá bọ́ọ̀lu tennis, tí ó gbá tennis fún Bermuda tí ó sì gba Àmì Bronze fún Orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà ni Eré Maccabian tí wọ́n gbá ní ọdún 1985 tó sì ṣe aṣojú ìlú South Africa ni ère Tennis, yàtò sì èyí ó ṣe déédéé èyí tí wọn fi mú láti wá nínú French Open. [4][2][3][5][6]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeMarks fi ìgbà kan jẹ́ Ọ̀gá Àgbà CEO àti Olùṣe ilé iṣẹ́ Lana Marks, tí ó jẹ́ ilé ìṣe fún àwọn ohun oge ṣíṣe ìgbàlódé tí ó ń ṣe àwọn Oríṣiríṣi ÀWỌ̀, tí ó sì jẹ́ gbajúmọ̀ níbi ká ṣe àwọn Báàgì olówò iyebíye tí ó sì gbowó lórí.[7][8][9]Nígbà tí Helen Miren gbáma Àmì Ẹ̀yẹ ni Academy Award ni ọdún 2017, ọkàn lára àwọn orísìírísìí báàgì tí Marks gbé jáde ní ó gbé lọ sí orí ìtàgé ìgbà Àmì Ẹ̀yẹ lọ̀dùn náà.[2] Lọ́wọ́ Lọ́wọ́ báyìí, ọmọ rẹ̀ ni ó ń darí ilé iṣẹ́ náà.[10] The Lana Marks company has stores in Palm Beach, New York, Beverly Hills, and Dubai.[6]
Ambassador sí South Africa
àtúnṣeÌpinnu láti jẹ̀ kí Marks di Asoju jẹyọ láti orísun kàn láàárín Ẹ̀ka ti Ìbátan Káríayé àti Ifowosowopo]], Ẹka Ọran ajeji ti South Africa.[11]Ní ọjọ́ kẹrìnlá, Oṣù Kọkànlá ọdún 2018, Ààrẹ tí ìlú Amẹ́ríkà Donald Trump yàn Marks gẹ́gẹ́ bí aṣojú ilé Amẹ́ríkà sì South Africa. Marks ti mọ Trump fun ogún ọdún, tí Ó sì jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ Mar-a-Lago tí Donald Trump.[12]Wọ́n fọwọ́ sì yí yàn rẹ̀ ni ilé Aṣojú Àgbá ni ọjọ́ kẹrìnlọ́gbọn, oṣù Kẹ̀sán, odun 2019.[13] She was sworn into office on October 4, 2019,[14]tí ó sì dé ibi ìṣe níjọ́ Kẹ̀sán oṣù kọkànlá ọdún 2019, tí Wọ́n sì gbé àwọn ìwé Ẹ̀rí rẹ̀ lọ sí ọ̀dọ Ààrẹ Cyril Ramaphosa ni Ọjọ́ Kejìlélọ́gbọ̀n, oṣù Kínní , ọdún 2020.[15][1] Marks tí jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ Mar-a-Lago tí Donald Trump Láti ọdún 2010.[16] Ó Wà Lára àwọn tí Donald Trump yàn látara àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Mar-a-Lago láti bá ṣe ìjọba.[17]
Marks jẹ́ kí á mọ̀ pé ohun tí ó jẹ́ òun lógún jùlọ jù ni àwọn Agbára Ọ̀dọ́ àti àwọn Obìnrin.[18] Ní àkọ́kọ́ Ọgọ́ta ọjọ́ tí ó kọ́kọ́ lọ, Marks ṣe ifilọlẹ awọn Ohun méjì, èyí tó sì pe gbogbo àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Áfríkà wá sí àpérò kan ni Washington D. C tí ó pè ní U. S - Africa Investment Summit àti láti gbé orílè èdè south Africa de ipò tí yóò fi wà lára àwọn alábaṣepọ̀ ìṣòwò Amẹ́ríkà tí ó ga jù lọ.[1]
Ni oṣù Kẹsàn-án ọdún 2020, àwọn orísun tí à kò ní dárúkọ tí orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà sọ pé Orílẹ̀ èdè Ìran ń gbèrò láti pa Marks ni South Africa. Wọ́n jẹ́ kí á mọ̀ pé orísun yìí pé, wọ́n gbèrò yìí láti gbẹ̀san àjálù bomb tí ó ṣe kú pá Qasem Soleimani tí ó jẹ́ Alákóso tẹ́lẹ̀ rí fún Àwọn Ológun Qods àti ìgbà kejì rẹ Abu Mabdi al Muhandis ni ọjọ́ kẹta, oṣù Kínní ọdún 2020 èyí tíó ṣẹlẹ̀ ni Baghbad ni ilú Iraq.[19]Àdàkọ:Dubious Ìbuwọ́lù lẹ́tà tí èrò inú rẹ wà láàárín U.S. International Development Finance Corporation (DFC) àti NuScale, láti ṣe ìdàgbàsókè 2,500 MW tí ó ní agbara iparun níSouth Africa, ní a tọka sí pé ó jẹ ọkàn nínu àwọn àṣeyọrí pàtàkì jù lọ rẹ̀.[20]
Ní oṣù kẹta ọdún 2020, Marks kọ̀ láti wà ní ìyà sọ́tọ̀ lẹ́hìn tí ó fara hàn sí COVID-19 ayẹyẹ kan tí ó wáyé nínú ọgbà Mar-a-Lago, tí Donald Trump sì jẹ́ Alákòóso ibè ni Florida.[21] Ní oṣù Kejìlá ọdún 2020, Marks wá ní ìyà sọ́tọ̀ fún ọjọ́ mẹ́wàá lórí àárun Covid-19 pẹ̀lú ìtọ́jú tó péye.[22] Gẹ́gẹ́ bí ẹni tí Donald Trump yàn fún Ìṣèlú rẹ gẹ́gẹ́ bí aṣojú, ó fi ipò ìṣe sílè nígbà tí wọ́n yàn Joe Biden gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ni ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù Kínní ọdún 2021, lẹ́yìn tí wọ́n fa John Groake sí ipò gẹ́gẹ́ bí aṣojú 'Charge d'Affaires ad interim.[23]
Ìgbé Ayé
àtúnṣeMarks jẹ́ iyawo sí Dókítà Neville Marks, oníwòsàn ọpọlọ tí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Ilé ìwòsàn JFK ní Atlantis ni ilú Florida, lati ọdún 1976.[24] Marks and her husband later lived in Bermuda before moving to Florida in 1987.[2][6] Ó sì bí àwọn ọmọ méjì.[25]
Marks jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́ tímọ́ sì Ọmọ Ọba Diana tí ìlú Wales. [26] Gẹ́gẹ́ bí ohun tí Marks sọ, àwọn obìnrin méjèèjì tí ṣètò láti lọ sí ìrìn àjò ọlọ́jọ́ mẹ́rin lọ sí orílẹ̀ èdè Italy tí ó bá di ìparí oṣù kẹjọ ni odun 1997. Ṣùgbọ́n Mark yí ohùn padà nígbà tí ó di ìṣẹ́jú tí wọ́n fẹ́ gbéra fún ìrìn àjò náà nítorí pé Baba Marks ni ìkọlù Ọ̀kàn. Diana lọ sí Paris Pẹ̀lú Àfẹ́sọ́nà rè Dodi Fayed níbi tí wọ́n tí padànu èmi wọn nínú ìjàmbá ọkọ̀. [27]
Láti ọdún 2010 Marks tí jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Mar-a-Lago. Ó dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ náà nítorí pé àwọn oríṣi ẹgbẹ́ mìíràn tí ó wà ní Palm Beach ni Florida ò gbà àwọn tí wọ́n bá jẹ́ Júù.[28][29]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 Fabricius, Peter (2020-01-31). "The Interview: US ambassador's ambition: Lift SA into top 20 of US trade partners" (in en). Daily Maverick. https://www.dailymaverick.co.za/article/2020-01-31-us-ambassadors-ambition-lift-sa-into-top-20-of-us-trade-partners/.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 Sommer, Allison Kaplan (November 22, 2018). "The Long, Strange Journey of Lana Marks, Trump's Pick for South African Ambassador". Haaretz. https://www.haaretz.com/us-news/.premium-the-long-strange-journey-of-lana-marks-trump-s-pick-for-south-african-ambassador-1.6674935.
- ↑ 3.0 3.1 Gaouette, Nicole; Landers, Elizabeth (2018-11-04). "Trump picks handbag designer, Mar-a-Lago member to be envoy to South Africa". CNN (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-11-16.
- ↑ Sommer, Allison Kaplan (November 22, 2018). "The Long, Strange Journey of Lana Marks, Trump's Pick for South African Ambassador". Haaretz. https://www.haaretz.com/us-news/.premium-the-long-strange-journey-of-lana-marks-trump-s-pick-for-south-african-ambassador-1.6674935.
- ↑ Munzenrieder, Kyle (October 22, 2018). "Lana Marks: The Handbag Designer Trump Reportedly Wants to Make Ambassador to South Africa". W. https://www.wmagazine.com/story/lana-marks-donald-trump-ambassador-to-south-africa.
- ↑ 6.0 6.1 6.2 Bleby, Michael (October 1, 2018). "We spoke to handbag designer and soon-to-be US ambassador to SA: this is what she said" (in en-US). BusinessDay. https://www.businesslive.co.za/bd/national/2018-10-01-in-2006-we-spoke-to-handbag-designer-and-soon-to-be-us--ambassador-to-sa-this-is-what-she-said/.
- ↑ Puri, Madhu (3 December 2006). "Now Gifting - Bespoke Bags". The New York Times. https://www.nytimes.com/2006/12/03/style/now-gifting-bespoke-bags.html.
- ↑ Prabhakar, Hitha. "World's Most Extravagant Handbags". forbes.com. Retrieved 4 April 2018.
- ↑ Burt, Sharelle (November 15, 2018). "Trump Nominates Handbag Designer As Ambassador To South Africa". Travel Noire. Retrieved 2018-11-16.
- ↑ Donnelly, Shannon. "Call her 'Madame Ambassador'". Palm Beach Daily News.
- ↑ Washington, Jason Burke Sabrina Siddiqui in (October 2, 2018). "Trump reportedly picks handbag designer as ambassador to South Africa". The Guardian. https://www.theguardian.com/us-news/2018/oct/02/lana-marks-trump-us-ambassador-south-africa.
- ↑ "Officials: Iran weighs plot to kill U.S. ambassador to South Africa". www.politico.com. 13 September 2020. Retrieved 2020-09-14.
- ↑ "President Donald J. Trump Announces Intent to Nominate and Appoint Individuals to Key Administration Posts | The White House" (in en-US). whitehouse.gov. Archived from the original on 2021-01-20. https://web.archive.org/web/20210120202318/https://trumpwhitehouse.archives.gov/presidential-actions/president-donald-j-trump-announces-intent-nominate-appoint-individuals-key-administration-posts-2/.
- ↑ Àdàkọ:Cite tweet
- ↑ [1], Lana Marks Returns to South Africa as US Ambassador.
- ↑ Gramer, Robbie (February 5, 2020). "At Embassies Abroad, Trump Envoys Are Quietly Pushing Out Career Diplomats" – via www.foreignpolicy.com.
- ↑ "The long, strange journey of Lana Marks, Trump's pick for South African ambassador" (in en). Haaretz. https://www.haaretz.com/us-news/.premium-the-long-strange-journey-of-lana-marks-trump-s-pick-for-south-african-ambassador-1.6674935.
- ↑ [2], US Ambassador Lana Marks Takes Short Left In Soweto.
- ↑ Toosi, Nahal (September 13, 2020). "Officials: Iran weighs plot to kill U.S. ambassador to South Africa" (in en-US). Politico. https://www.politico.com/news/2020/09/13/iran-south-africa-ambassador-assassination-plot-413831.
- ↑ Fabricius, Peter (21 January 2021). "United States Ambassador Departs Pretoria". Daily Maverick. Retrieved 25 January 2021.
- ↑ Jakes, Lara (2020-11-01). "U.S. Diplomat Coughs Online, and European Allies Wonder if They Were Exposed" (in en-US). The New York Times. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/2020/11/01/us/politics/coronavirus-state-department-diplomats.html.
- ↑ Meldrum, Andrew (11 January 2021). "US Ambassador in South Africa Better after ICU Virus Care". AP News. Associated Press. Retrieved 25 January 2021.
- ↑ "US envoy to SA: Amid change, an enduring partnership will remain". U.S Embassy & Consulates in South Africa. 21 January 2021. Retrieved 21 January 2021.
- ↑ "Dr. Neville MarksMD".
- ↑ Durkin, Tish (February 3, 2019). "Talking With Lana Marks, Who's Ready to Ditch Palm Beach for Pretoria". Intelligencer.
- ↑ "Time, February 2 1998". time.com. Archived from the original on 30 April 2009. Retrieved 4 April 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Feitelberg, Rosemary (2018-11-15). "Lana Marks: The Makings of a Fashion-Focused Ambassador nominee" (in en-US). WWD. https://wwd.com/eye/people/lana-marks-the-makings-of-a-fashion-focused-ambassador-nominee-1202908159/.
- ↑ Durkin, Tish (February 3, 2019). "Talking With Lana Marks, Who's Ready to Ditch Palm Beach for Pretoria". Intelligencer.
- ↑ Roberts, Roxanne (January 8, 2019). "Palm Beach used to be a nice town for billionaires. Then Trump came along.". The Washington Post. Retrieved March 21, 2020.