The Landmark Leisure Beach, tí ó wà ní Plot 3 àti 4 Water Corporation Road - VI jẹ́ àkọ́kọ́ ní ìlú Èkó tó jẹ́ aládàání iwájú etí òkun. Àwọn ẹ̀yà etí òkun yìí ni boardwalk láàrín Atlantic coastline, èyí tí ó mú ìjìnnà ààyè ti Landmark Village wáyé, ilé sí Hardrock Café, Shiro Restaurant, àwọn ọgbọ́ntarìgì Landmark Event Centre àti èyí tí wọ́n má dá lẹ̀ "Retail Boulevard". Ó ṣàjọ̀pọ̀ ẹgbẹ́ẹgbẹ̀rún àwọn eré ìdárayá àti àwọn iṣẹ́ eré ìdárayá èyítí ó ṣáájú fún àwọn àgbàlagbà àti àwọn ọmọdé. [1]

IṢẸ́ GBAJÚMỌ̀

àtúnṣe

Lórí ilẹ̀ tàbí ní òkun, Landmark Leisure Beach ti kún pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ ṣíṣe fún àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí.

Àwọn Ìtọ́ka Sí

àtúnṣe
  1. "landmarkbeach". landmarkbeach. Archived from the original on 2022-09-20. Retrieved 2022-09-15.