Lasisi Elenu

apanilẹrin ati oṣere Naijiria

Nosa Afolabi, tí a mọ̀ sí Lasisi Elenu, jẹ́ apanilẹ́rìn-ín, òṣèré, àti ohun tí àwọn olóyìbó mọ̀ sí "compere" [1][2] látí Offa, ní Ìlú Kwara ní Ilẹ̀ Nàìjíríà. Ọ̀kan nínú àwọn èèyàn tó ní ipá olókìkí jùlọ ní Áfíríkà, ó jẹ́ olókìkí fún àwọn eré apanilẹ́rìn-ín ṣókí rẹ̀ pẹ̀lú àlẹmọ 'ẹnu jákéjádò' ní àkókò tó bá ń ṣeré àti lórí mídíà ẹ̀rọ ayélujára. [3] during performances and on social media. Elenu ti ṣe ìfihàn láìpẹ́ ní aṣaragágá Netflix, The Ghost and the Tout.[4][5]

Lasisi Elenu
Ọjọ́ìbíNosa Afolabi
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ilorin
Iṣẹ́Comedian and actor

Ní ọdún 2018, ó jẹ́ yíyan fún ẹ̀bùn ayẹyẹ Future Awards Africa fún eré apanilẹ́rìn-ín. [6][7][8][9] Ní oṣù kẹta ọdún 2020, ó jẹ́ orúkọ ọ̀kan nínú Top 25 Under-30 Nigerian SuperStars. [10] Ó sì jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn tó borí apá kejì ti Trendupp Awards. [11][12][13]

Àwọn Ìtọ́ka Sí

àtúnṣe
  1. "Lasisi Elenu (Nosa Afolabi)'s schedule for Social Media Week Lagos". socialmediaweeklagos2018.sched.com. Retrieved 12 November 2020. 
  2. "Lasisi Elenu: I am excited for keeping people entertained | The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News — Saturday Magazine — The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News". guardian.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-12-04. Retrieved 2022-12-04. 
  3. "Female fans usually ask me for sex –Musa Afolabi, comedian". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 November 2020. 
  4. "The Ghost and the Tout | Netflix". www.netflix.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 November 2020. 
  5. Online, Tribune (2018-04-15). "Toyin, Lasisi Elenu, Chiwetalu Agu, star in ‘The Ghost and the Tout’". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-04. 
  6. "The Future Awards Africa Prize for Comedy". The Future Awards Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2 December 2018. Archived from the original on 12 November 2020. Retrieved 12 November 2020. 
  7. "The Future Awards Africa 2018 Nominees List". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-05. Archived from the original on 2018-12-27. Retrieved 2022-12-04. 
  8. Online, The Eagle (2018-12-03). "Burna Boy, Adesua Etomi, Maraji others make 2018 The Future Awards nominee list -". The Eagle Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-04. 
  9. Report, Agency (2018-12-03). "Burna Boy, Adesua Etomi, Maraji others make 2018 Future Awards list". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-04. 
  10. "See Who Made Top 25 Under-30 Nigerian Superstars". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 4 March 2020. Retrieved 12 November 2020. 
  11. Online, Tribune (2022-06-14). "Mr Macaroni, Lasisi Elenu, Miss Techy, Aproko doctor, others emerge winners at Trendupp awards 2022". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-04. 
  12. "Macaroni, Lasisi Elenu, Miss Techy, Others Emerge Winners at Trendupp Awards 2022 – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2022-12-04. 
  13. "Trendupp Awards 2022: Lasisi Elenu, Kiekie, Aproko Doctor others emerge winners - The Trumpet Nigeria - Latest Nigeria News, Business News Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-06-24. Retrieved 2022-12-04.