Lateefat Okunnu
Lateefat Modupe Okunnu (tí a bí ní December 3, 1939) jé osise ìjoba Nàìjíríà tí o ti feyinti, ó sì jé ígbákejì Gomina ti ìpinlè Eko larin odun 1990-1992. Okunnu jé ara àwon omo egbé àkókò ti Federation of Muslim Women's Associations in Nigeria (FOMWAN).[1]
Lateefat Okunnu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Lateefat Okunnu 3 Oṣù Kejìlá 1939 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Civil servant |
Gbajúmọ̀ fún | Ígbákejì Gomina Ìpínlẹ̀ Èkó |
Àárò ayé àti èkó rè
àtúnṣeA bí Okunnu silu Èkó kí o tó dipe olo ilé-ìwé Primari Okepopo, Lagos island fún eko primari rè, ó sì tèsíwájú ní ilé-ìwé Methodist Girl's High School àti Queens College, Yaba.[2] O gbà àmì-èye Bachelor of Arts nínú ìmò Geography àti postgraduate diploma in education ní yunifásitì ìlú Eko ni odun 1968.[3]
Isé rè
àtúnṣeLaarin odun 1967 sí odun 1970, Okunnu sísé ní Yunifásitì ìlú Eko gegebi olùkó, o tún sisé ní èka ijoba Naijiria to ri sí ètò nkan ogbin, o di akowe èka náà ní odun 1986.[4] Okunnu wà lara àwon obinrin tí o dá egbe Federation of Muslim women kalè ní Nàìjirià, òun ni okoko di ígbákejì ààré ajo náà, oun sì ni olori èka ti Eko. Ni odun 1989, Okunnu di àárè àjo náà. Ní odun 1990, a yàn gegebi ígbákejì Gomina ti Eko, òun àti Pamela Saraki ti ìpinlè Kaduna jé obinrin àkókó tí a yan sípò náà.[4]
Àwon ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Nigerian youths are too artificial –Alhaja Okunnu". National Mirror. 2013-03-23. Archived from the original on 2013-03-23. Retrieved 2022-05-30. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "QC unveils Hall of Fame, solar water project". Vanguard News. 2016-12-14. Retrieved 2022-05-30.
- ↑ Faseke, M. (2005). Nigerian Women Professionals: A Historical Analysis. Tidings Publications. ISBN 978-978-067-170-9. https://books.google.com/books?id=0rAEAQAAIAAJ. Retrieved 2022-05-30.
- ↑ 4.0 4.1 "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2016-08-10. Retrieved 2022-05-30.