Latifat Tijani (ti a bi ni ọjọ Kẹjo oṣu kọkanla ọdun 1981) jẹ elere idaraya agbara gbigbe orilẹ-ede Naijiria . O gba goolu ninu idije awọn obinrin – 45kg ti ere Afirika ni odun 2015 ni Brazzaville, Republic of Congo . Ni ọdun 2016, o dije ninu ìdíje àwọn obinrin ni ipele – 45kg ni olimpiki àwọn akanda eda ti igba ooru ọdun 2016, nibi ti o ti gbe 106kg lati gba fadaka. [1] [2]

Latifat Tijani
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kọkànlá 1981 (1981-11-08) (ọmọ ọdún 43)
Weight43 kg (95 lb)

Ni dije World Para Powerlifting ti ọdun 2019 o bori ti o si gba ami-idẹ idẹ ni ipele 45 kg ti awọn obinrin.

Awọn itọkasi

àtúnṣe