Laurent-Désiré Kabila
Aare Kẹta ti Democratic Republic of Congo
(Àtúnjúwe láti Laurent Kabila)
Laurent-Désiré Kabila (27 Osu Kokanla 1939 – 18 Osu Kinni 2001) je Aare ti Orile-ede Olominira Toseluarailu ile Kongo lati ojo 17 Osu Karun 1997, nigba to gbajoba lowo Mobutu Sese Seko, titi di igba ifikupawo re latowo awon oluso re ni ojo 18 Osu Kinni 2001. O je riropo latowo omokunrin re Joseph.
Laurent-Désiré Kabila | |
---|---|
Aare OOT ile Kongo | |
In office May 17, 1997 – January 18, 2001 | |
Asíwájú | Mobutu Sese Seko (as President of Zaire) |
Arọ́pò | Joseph Kabila Kabange |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Baudouinville, Kongo Beljiom | 27 Oṣù Kọkànlá 1939
Aláìsí | 18 January 2001 Kinshasa, OOT Kongo | (ọmọ ọdún 61)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | AFDL |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Sifa Mahanya |
Profession | Rebel leader |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |