Layipo Ibadan
(Àtúnjúwe láti Layipo)
Layipo Ibadan tàbí Láípo, tí a tún mọ̀ sí Bower's Tower, jẹ́ ilé gíga sooro tí wọ́n kọ́ sí Òkè-àrẹ ní ìlú Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, in southwestern Nigeria. [1] Wọ́n kọ́ Ilé gíga sooro lọ́dún 1936 [2] láti bọlá fún Captain Robert Lister Bower, ọmọ orílẹ̀ èdè Britain àkọ́kọ́ tí ó gbé ní Ibadan
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Tourism: Journey from Ibadan to Layipo". Tribune Online. 2021-01-02. Retrieved 2024-07-06.
- ↑ "Layipo: The heritage of Ibadan". TheCable. 2019-05-01. Retrieved 2024-07-06.