Lazarus Muoka jé òlùsóagutan ní orilede Naijiria, ajihinrere pelu òǹkọ̀wé.[1] O je oludasile ati oludari fun The Lord’s Chosen Charismatic Revival Movement.[2][3]

Ìgbésí ayé rẹ̀ àti iṣẹ́ tó yàn láàyò

àtúnṣe

Wọ́n bí Lazarus Muoka sínú ìdílé Catholic, ní Umuhu-Okabia tó wà ní Orsu LGA ti Orlu zone ní Ìpínlẹ̀ Ímò, níbi tí ó ti lọ parí ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ti girama. Ní ọdun 1975, ó kó wá sí Ìpínlẹ̀ Èkó, ó sì ṣiṣẹ́ fún ìgbà díẹ̀ ní ilé-iṣẹ́ kan kí ó tó bèrè ìdókòwò rẹ̀ tí ó ṣe títí ó fi fi ayé rẹ̀ fún Kristi gẹ́gẹ́ bí i Kìrìsìtẹ́ẹ́nì pípé.[4]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Lazarus Muoka Biography". Retrieved 26 October 2018. 
  2. "Pastor Lazarus Muoka speaks In Lord's Chosen apron". Wole Balogun. The Sun News. 12 January 2015. Archived from the original on 13 July 2015. Retrieved 13 July 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Ihejirika, Walter C., and Godwin B. Okon. "Mega Churches and Megaphones: Nigerian Church Leaders and Their Media Ministries." A Moving Faith: Mega Churches Go South (2014): p. 62.
  4. "Pastor Lazarus Muoka speaks in Lord's Chosen apron". The Sun. 12 January 2013. Archived from the original on 13 July 2015. Retrieved 13 July 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)