Lebogang Phalula tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀san Oṣù kejìlá ọdún 1983 jẹ́ olùsáré ọlọ́nàjínjìn fún orílẹ̀ ède South Africa kan .

Lebogang Phalula
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbíỌjọ́ kẹẹ̀sán osù kejìlá Ọdún 1983 (Ọdún Méjìdínlógójì)
Sport
Orílẹ̀-èdèSouth Africa
Erẹ́ìdárayáEré sísá ọ̀nà jíjìn

Ní ọdún 2009, ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin àgbà fún IAAF World Cross Country Championships ti 2009 tí ó wáyé ní Amman, Jordani. O pari pẹ̀lú ipò kọkàndínlọ́gbọ̀n. [1]

Ní ọdún 2009, ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin àgbà fún IAAF World Cross Country Championships ti 2009 tí ó wáyé ní Amman, Jordani. O pari pẹ̀lú ipò kọkàndínlọ́gbọ̀n. [1]

Ní ọdún 2011, o gba ìdádúró oṣù mẹ́fà ní bí eré ìdárayá léyìn tí wọ́n rí wípé àyẹwò fi hàn wípé o ní methylhexaneamine ti a fi òfin dé.

O jáwé Olúborí fún eré ọgọ́ọ̀rún mẹ́jọ mítaà tí a sọ àkọ́lé rẹ̀ níbi 2005 South African athletics championships . [2]

ó ní ọmọ ìyá bìnrin tí ó jẹ́ Ìbejì rẹ̀ tí òhun náà jẹ́ eléré ìdárayá tí à n pè ní Dina Lebo Phalula . [3]

  • Àkójọ ìṣẹ̀lẹ̀ tí kò hàn gbangbanínú àwọn eré ìdárayá

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named senior_women_race_iaaf_world_cross_country_championships_2009
  2. South Africa championships, Durban 15-17/04. Africa Athle. Retrieved 2021-01-23.
  3. Buthelezi, Mbongiseni (2019-09-04). Phalula twins aim for Tokyo via Cape Town. IOL. Retrieved 2021-01-23.

ìjápọ ìta

àtúnṣe
  • Lebogang Phalula ní World Athletics