Lech Wałęsa

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Poland.
(Àtúnjúwe láti Lech Walesa)

Lech Walesa (Pl-Lech_Wałęsa.ogg [ˈlɛx vaˈwɛ̃sa] ; ojoibi 29 September 1943) je oloselu omo orile-ede Polandi, alakitiyan tele fun egbe irepo onisowo ati eto omo eniyan. O gba Ebun Nobel fun iwa alafia ni 1983, o si je Aare ile Polandi lati 1990 titi di 1995.[1]

Lech Wałęsa
Aare ile Polandi
In office
22 December 1990 – 22 December 1995
Alákóso ÀgbàTadeusz Mazowiecki, Jan Krzysztof Bielecki, Jan Olszewski, Waldemar Pawlak, Hanna Suchocka, Józef Oleksy
AsíwájúWojciech Jaruzelski (in country) Ryszard Kaczorowski (in exile)
Arọ́pòAleksander Kwaśniewski
1st Chairman of Solidarity
In office
1980 – 12 December 1990
AsíwájúN/A
Arọ́pòMarian Krzaklewski
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kẹ̀sán 1943 (1943-09-29) (ọmọ ọdún 81)
Popowo, Poland)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúSolidarity
(Àwọn) olólùfẹ́Danuta Wałęsa
ProfessionElectrician