Leila Aman ni a bini ọjọ kẹrin leelogun, óṣu November, ọdun 1977 ni Arsi jẹ elere sisa ti ọna jinjin órilẹ ede Ethiopia[1].

Àṣèyọri àtúnṣe

Ni ọdun 2003, Leila kopa ninu ere gbogbo ilẹ Afirica to waye ni Abuja, órilẹ ede Naigiria ti arabinrin naa si gbè ipo kẹta[2][3].

Ni ọdun 2004, Leila kopa ninu marathon ti Dubai ni bi ti arabinrin naa si gbè ipo akọkọ[4].

Itọkasi àtúnṣe

  1. Leila AMAN Profile
  2. ALL-AFRICA GAMES
  3. Women Marathon Athletics VIII All Africa Games Abuja (NGR) 2003
  4. Dubai Marathon