Leila Nakabira
Leila Nakabira (bíi ni ọdún 1993) jẹ́ òṣèré àti ajìjàgbara fún àwọn obìnrin ní orílẹ̀ èdè Uganda.[1][2] Òun ni olùdarí Lepa Africa Films. Òun ni olùdásílẹ̀ Nakabira for Charity Foundation.[3]
Leila Nakabira | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Leila Nakabira 1993 Uganda |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Makerere University, Kampala |
Iṣẹ́ | Actress • Scriptwriter • Women activist |
Gbajúmọ̀ fún | The Forbidden (2018) |
Ẹ̀kọ́
àtúnṣeNakabira gboyè nínú Quantitative Economics láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Makere University.[4]
Iṣẹ́
àtúnṣeWọ́n yàán Nakabira fún àmì ẹ̀yẹ mẹ́ta: Best Golden Actress (Drama), Golden Most Promising Actor and Golden Discovery Actor níbi ayẹyẹ Golden Movie Award Africa tí wọ́n ṣe ní ọdún 2018.[5][6] Ní ọdún náà, wọ́n tún yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti Zulu Africa Film Academy Award fún ipa tí ó kó nínú The Forbidden[7]. Ó gbà àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ UDADA Women's Film Award ní ọjọ́ ogún, oṣù kẹwàá ọdún 2018.[8] Ní ọdún 2019, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ The African Film Festival (TAFF) Awards[9][10] àti Lake International Film Festival (LIPFF).[11]
Àwọn Ìtọ́kàsi
àtúnṣe- ↑ "'Just do it' says Ugandan actress on African Women's Day". RFI. July 31, 2019. Retrieved November 3, 2020.
- ↑ Murungi, Dorcus (February 6, 2019). "Curvy, sexy Ugandan women named new tourist attraction". Scoop. Retrieved November 4, 2020.
- ↑ Ruby, Josh (November 5, 2019). "Fingers Crossed! Leilah Nakabira Kenya-bound for LIPFF awards". MBU. Retrieved November 3, 2020.
- ↑ "Formal training and qualifications add depth to your natural talents". Daily Monitor. February 14, 2020. Retrieved November 3, 2020.
- ↑ Ruby, Josh (May 23, 2018). "Leilah Nakabira nominated thrice in the 2018 Golden Movie Awards". MBU. Retrieved November 3, 2020.
- ↑ "2018 Golden Movie Awards Africa nominations announced". ScooperNews. May 21, 2018. Retrieved November 4, 2020.
- ↑ Ruby, Josh (October 22, 2018). "Leilah Nakabira bags first award at the UDADA Film Festival". MBU. Retrieved November 3, 2020.
- ↑ Ruby, Josh (October 22, 2018). "Leilah Nakabira bags first award at the UDADA Film Festival". MBU. Retrieved November 3, 2020.
- ↑ "Diana Nabatanzi Nominated In The African Film Festival Awards In US". GLIM. June 18, 2019. Archived from the original on November 4, 2021. Retrieved November 3, 2020.
- ↑ Ruby, Josh (July 3, 2019). "Leila Nakabira and Claire Nampala win big at TAFF awards in USA". MBU. Retrieved November 3, 2020.
- ↑ Ruby, Josh (November 5, 2019). "Fingers Crossed! Leilah Nakabira Kenya-bound for LIPFF awards". MBU. Retrieved November 3, 2020.