Len Deighton bibliography

Len Deighton (bíi Ọjọ́  kejídínlógún Oṣù kejí ọdún 1929) jẹ́ olùkọ̀tàn gẹ̀ẹ́sì tí wọ́n mọ̀ sí àwọn ìwé àkàkọ́gbọ́n, àwọn iṣẹ́ ìtàn ológun, ìfàwòránsọ̀tàn àtí kíkọ nípa bí a ṣe ń se oúnjẹ́. Ó ní oríṣiriṣi iṣẹ́, iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú àkàra díndín, agbáwo oúnjẹ, ara àwọn olùkọ̀wé ìròyín, olùkọ́ àti ara àwọn to ń ṣiṣẹ́ nínú ọkọ̀ òfurufú kí ó tó kọ  àkọ́kọ́ ìwé àkàkọ́gbọ́n rẹ̀ ní ọdún 1962: The IPCRESS File.[1][2]  Ó ń tẹ̀síwájú ṣe o oun tí olùkọ̀tàn ìgbésíayérẹ̀ pè ní "oge, àwàdà, ìwé àkàkọ́gbọ́n tó dára ní ìtan ọfintótó,[3]  pẹ̀lú àwọn ìwé àkàkọ́gbọ́n kí ó to ṣàfihàn Bernard Samson.[4][lower-alpha 1]

Deighton kọ ìwé amóùnmáwòran méjì, tí àkọ́kọ́ rẹ̀ jẹ́ Long Past Glory ní Ọdún 1963; ó tún kọ ìwé Oh! What a Lovely War (1969). Ó nífẹ́ sí oúnjẹ́ sísè tipẹ́tipẹ́ — Ìyá rẹ̀ jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n oúnjẹ sísè tí o ́ sì fi ìfẹ́ oúnjẹ sísè yìí sínú ọmọ rẹ̀—jẹ́ kí ó ń ojú ewé tí wọ́n ti ma ń kọ nípa oúnjẹ sísè ní ìwé ìróyìn tí ó ma ń jade lọ́jọ́ ọ̀sẹ̀,The Observer, fún ọdún méjì. Wọ́n kó àwọn iṣẹ́ yìí pọ̀ sínú àwọn ìwé méjì kan, Len Deighton's Action Cookbook àti Où est le garlic (méjèèjì ní ọdún 1965); ó tún kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé nípa oúnjẹ sísè.[5] Deighton ti ṣàgéjáde oríṣiríṣi àwọn iṣẹ́ míràn bíi ẹ̀kọ́ nípa  bí wọ́n ṣe ṣọ́ John F. Kenedy pa, ìtan òfúrufú, Ìtàn Ogun Àgbáyé Kejì àti ìwé ojú òpó nípa James Bond.[6][7]

Àwọn ìwé àkàkọ́gbọ́n

àtúnṣe
The novels of Len Deighton
Àkọ́lé[1][8][9]
Ọdún tí wọ́n kọ́kọ́ gbe jáde
Alágéjáde àkọ́kọ́

(Gbogbo rẹ̀ ní London)

IPCRESS File !The IPCRESS File 1962  ! 1962 Hodder & Stoughton
Horse Under Water 1963  !1963
Jonathan Cape
Funeral in Berlin 1964  !1964
Jonathan Cape
Billion-Dollar Brain 1966  !1966
Jonathan Cape
Expensive Place to Die !An Expensive Place to Die[lower-alpha 2] 1967.1  !1967
Jonathan Cape
Only When I Larf 1967.2  ! 1967 Privately printed[lower-alpha 3]
Bomber 1970  ! 1970 Jonathan Cape
Close-Up 1972 ! 1972 Jonathan Cape
Spy Story 1974  ! 1974 Jonathan Cape
Yesterday's Spy 1975  ! 1975 Jonathan Cape
Twinkle, Twinkle, Little Spy 1976       ! 1976 Jonathan Cape
SS-GB 1978        ! 1978 Jonathan Cape
XPD 1981  ! 1981 Hutchinson
Goodbye, Mickey Mouse 1982   !1982
Hutchinson
Berlin Game 1983   !1983
Hutchinson
Mexico Set 1984        ! 1984 Hutchinson
London Match 1985          !1985
Hutchinson
Winter 1987         ! 1987 Hutchinson
Spy Hook 1988       ! 1988 Hutchinson
Spy Line 1989       ! 1989 Hutchinson
Spy Sinker 1990       ! 1990 Hutchinson
MAMista 1991.1         !1991
Random House
City of Gold 1991.2       !1991
Random House
Violent Ward 1993       ! 1993 HarperCollins
Faith 1994        !1994
HarperCollins
Hope 1995      !1995
HarperCollins
Charity 1996        ! 1996 HarperCollins

Oríṣiríṣi

àtúnṣe

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ Deighton ni wọ́n ti fi ṣe eré: Eré The Ipcress File (1965),[2] Funeral in Berlin (1966),[3] Billion Dollar Brain (1967)[4] àti Spy Film (1976).[5]  Ní ọdún 1988 amóùnmáwòran Granada ṣàgbéjáde miniseries Game, Set and Match tí ó dálórí àwọn ìwé àkàkọ́gbọ́n rẹ̀ mẹ́ta tí ó ń jẹ́ orúkọ kan náà.[6]

Àwọn oríṣiríṣi iṣẹ́ Deighton
Àkọ́lé[17][18]
Ọdún tí wọ́n kọ́kọ́ gbe jáde Alágéjáde àkọ́kọ́

(Gbogbo rẹ̀ ní London  àfi ti wọ́n bá ní kò ríbẹ́ẹ̀

Notes
Long Past Glory 1963.1       ! 1963 Television script[7]
Len Deighton's Cookstrips 1963.2        ! 1963 sí 1965 Observer !The Observer Weekly cookery strip[8][9]
Drinkmanship 1964 Haymarket Press As editor
Oh! What a Lovely War 1969 Film script; Deighton requested that he not be given screen credit for his work.[10]
Declarations of War 1971 Jonathan Cape Short stories
How to be a Pregnant Father 1977.1        !1977
Macmillan Publishers Book by Peter Mayle; Deighton provided the chapter "The Pregnant Father's Cookbook"
It Must Have Been Two Other Fellows 1977.2         !1977
Television script[3]
Tactical Genius in Battle 1979 Phaidon Press Book by Simon Goodenough; Deighton acted as editor and provided the introduction
Adventure of the Priory School !The Adventure of the Priory School 1985      ! 1985 Santa Teresa Press, Santa Barbara, CA Introduction only; original work by Arthur Conan Doyle. This edition was published for copyright purposes; limited to 25 copies
Pests 1994 Chris Martin, Mansfield Woodhouse, Notts A limited edition of 226 copies
Sherlock Holmes and the Titanic Swindle 2006 Crippen & Landru, Norfolk, VA A short story included in The Detection Club anthology The Verdict of Us All, edited by Peter Lovesey[11]

Àwọn tí kìí ṣe ìṣẹ̀tàn

àtúnṣe
Àwọn iṣẹ́ Len Deighton tí kìí ṣe ìṣẹ̀tàn
Àkọ́lé[1][8][9]
Ọdún tí wọ́n kọ́kọ́ gbe jáde Alágéjáde àkọ́kọ́ (Gbogbo rẹ̀ ní London àfi ti wọ́n bá ní kò ríbẹ́ẹ̀ Notes
Len Deighton's Action Cookbook 1965.1 !Ọdún 1965 Jonathan Cape
Où est le garlic 1965.2 !Ọdún 1965 Penguin Books
Assassination of President Kennedy !The Assassination of President Kennedy 1967.1 !Ọdún 1967 Jonathan Cape Co-written with M Rand and H Lockston
Len Deighton's London Dossier 1967.2 !Ọdún 1967 Jonathan Cape
Continental Dossier 1968 !Ọdún 1968 Michael Joseph
Fighter: The True Story of the Battle of Britain 1977.1 !Ọdún 1977 Jonathan Cape
Airshipwreck 1978 !Ọdún 1978 Jonathan Cape with Arnold Schwartzman
Blitzkrieg: From the Rise of Hitler to the Fall of Dunkirk 1979.1 !Ọdún 1979 Jonathan Cape
Basic French Cooking 1979.2 !Ọdún 1979 Jonathan Cape
Battle of Britain 1980.1 !Ọdún 1980 Jonathan Cape
Orient Flight !The Orient Flight 1980.2 !Ọdún 1980 Germany Philatelic Society, Chesterfield, MO As "Cyril Deighton"; with Fred Blau
Egypt Flight !The Egypt Flight 1981 !Ọdún 1981 Germany Philatelic Society, Chesterfield, MO As "Cyril Deighton"; with Fred Blau
ABC of French Food 1989 !Ọdún 1989 Century
Basic French Cookery Course 1990 !Ọdún 1990 Century
Blood, Tears and Folly 1993 !Ọdún 1993 Jonathan Cape
James Bond: My Long and Eventful Search for His Father 2012 !Ọdún 2012 Amazon Kindle In e-book format only[7]

Àwọn àkíyèsí àti ìtọ́kasí

àtúnṣe

Àwọn àkíyèsí

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 "Len Deighton". Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "Gage CA" defined multiple times with different content
  2. "The Ipcress File (1965)".
  3. "Funeral in Berlin (1966)".
  4. "Billion Dollar Brain (1967)".
  5. "Spy Story (1976)".
  6. "Game, Set and Match (1988)".
  7. "Long Past Glory (1963)".
  8. Stummer, Robin (14 December 2014). Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "Obs: cookstrip" defined multiple times with different content
  9. Walsh, John (17 June 2009). Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "Indie: cookstrip" defined multiple times with different content
  10. "Oh! What a Lovely War".
  11. "The Verdict of us All".
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tag with name "AFI: Larf" defined in <references> is not used in prior text.