Leo Tolstoy, tabi Count Lev Nikolayevich Tolstoy (Rọ́síà: Ru-Lev Nikolayevich Tolstoy.ogg Лев Никола́евич Толсто́й​ , Pípè ní èdè Rọ́síà: [lʲɛv nʲɪkɐˈlaɪvʲɪtɕ tɐlˈstoj]; September 9 [O.S. August 28] 1828 – November 20 [O.S. November 7] 1910), je olukowe ara orile-ede Russia to je gbigba gege bi ikan ninu awon olukotan aroko to je olokikijulo. Awon iwe re Ogun ati Alafia ati Anna Karenina.

Leo Tolstoy
Only color photograph of the novelist, shot at his Yasnaya Polyana estate in 1908 by Prokudin-Gorskii, a pioneer of color photography
Iṣẹ́Novelist
GenreRealist
Notable worksWar and Peace
Anna Karenina

Signature