Leonard Nangolo Auala (tí a bí ní ọjọ́ kàrùnlélógun oṣù Kẹ̀sán án ọdún 1908 ní Iiyale, Oniipa, Ovamboland, German South West Africa tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹrin oṣù Kejìlá ọdún 1983 ní Onandjokwe, South West Africa[3]) jẹ́ adarí ìjọ Lutheran nígbà ayé rẹ̀.

Àdàkọ:Pre-nominal styles Leonard Auala
Bishop
1967
ChurchEvangelical Lutheran Church in Namibia
Personal details
Born25 September 1908
Iiyale, Oniipa, Ovamboland, German South West Africa[2]
Died4 December, 1983
Onandjokwe Lutheran Hospital,[1] South West Africa

Ìpìlẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Auala ní Oniipa, Ovamboland, German South West Africa. A bi sí inú ìdílé Nakanyala Vilho yaAwala (Shihwa) waAmukwiyu àti Nekwaya Loide yaShikongo shaNangolo dhaAmutenya.[3]

Ó lọ ilé ìwé prámárì ní Oniipa láàrin ọdún 1919 sí 1929, a sì kọ nípa ìmọ̀ iṣé àlùfáà láàrin ọdún 1929 àti 1931. Ní 1934 sí 1935, o kàwé ní Augustineum, Okahandja, ó sì tún kọ́ nípa iṣẹ́ àlùfáà ní Elim ní ọdún 1942, Ní ibi tí a ti yán gẹ́gẹ́ bi àlùfáà.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Ihamäki, Kirsti (1985). Leonard Auala: Mustan Namibian paimen. Helsinki: Kirjaneliö. pp. 270–271. ISBN 951-600-677-9. 
  2. Kutsu Helsingin yliopiston teologisen tiedekunnan tohtoripromootioon marraskuun 2. päivänä 1967, p. 32. Helsinki, 1967.
  3. 3.0 3.1 Nambala, Shekutaamba V. V. (1995). Ondjokonona yaasita naateolohi muELCIN 1925–1992. Oniipa, Namibia: ELCIN. pp. 58–59.