Lepacious Bose
Bose Ogunboye gbọ́ (tí a bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gún oṣù kẹrin ọdún 1976) tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ sí Lepacious Bose jẹ́ aláwadà àti òṣèrébìnrin ní ilé isé Nollywood.[1][2] Ní ọdún 2014, ó gba àmì-ẹ̀yẹ 2014 Golden Icons Academy Movie Awards fún eré àwàdà rẹ̀ nínú fíìmù “Being Mrs Elliot”.[3][4]
Lepacious Bose | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Bose Ogunboye 17 Oṣù Kẹrin 1976 Ìlú Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Yunifásitì ìlú Ìbàdàn |
Iṣẹ́ |
|
Gbajúmọ̀ fún | Mrs Elliot |
Awards | 2014 Golden Icons Academy Movie Awards |
Àtòjọ àwọn fíìmù tí ó ti ṣeré
àtúnṣe- Makate Must Sell (ọdún 2019)
- 200 Million (ọdún 2018)
- Chief Daddy (ọdún 2018)
- Gidi Blues
- Gidi Blues (ọdún 2016)
- First Class (ọdún 2016)
- Being Mrs Elliot
- A Long Night (ọdún 2014)
- Tunnel (ọdún 2014)
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Only 'extra' men can openly love fat women, says comedienne Lepacious Bose". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-19. Retrieved 2022-07-23.
- ↑ "‘I made more money when I was fat’ – Lepacious Bose". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-07-01. Retrieved 2022-07-23.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ yaasomuah (2014-10-30). "Glitz & Glam: Golden Icons Academy Movie Awards (GIAMA)". Yaa Somuah (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-17. Retrieved 2022-07-23.
- ↑ "Best Nollywood movies of 2014". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-01-02. Retrieved 2022-07-23.