Lesego Moeng
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Lesego Gloria Moeng | ||
Ọjọ́ ìbí | ọjọ́ kẹta osù Kínní ọdún 1998 | ||
Ìga | 1.70 m[1] | ||
Playing position | Asọ́lé | ||
Club information | |||
Current club | BDF | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Geronah | |||
BDF | |||
National team‡ | |||
2021– | Botswana | 5 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Lesego Gloria Moeng tí a bí ní ọjọ́ kẹta osù Kínní ọdún 1998 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-ède Motswana kan tí ó mú ipò asọ́lé lórí pápá fún BDF àti ẹgbẹ́ àwọn obìnrin <a href="./Boolu-afesegba" rel="mw:WikiLink" data-linkid="81" data-cx="{"adapted":true,"sourceTitle":{"title":"Association football","thumbnail":{"source":"https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/a/ad/Football_in_Bloomington%2C_Indiana%2C_1996.jpg/80px-Football_in_Bloomington%2C_Indiana%2C_1996.jpg","width":80,"height":54},"description":"Team[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] sport played with a spherical ball","pageprops":{"wikibase_item":"Q2736"},"pagelanguage":"en"},"targetTitle":{"title":"Boolu-afesegba","thumbnail":{"source":"https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/a/ad/Football_in_Bloomington%2C_Indiana%2C_1996.jpg/80px-Football_in_Bloomington%2C_Indiana%2C_1996.jpg","width":80,"height":54},"pageprops":{"wikibase_item":"Q2736"},"pagelanguage":"yo"},"targetFrom":"link"}[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]" class="cx-link" id="mwDw" title="Boolu-afesegba">orílẹ̀-ède</a> Botswana .
Isẹ́ Ẹgbẹ́
àtúnṣeMoeng ti gbábọ́ọ̀lù fún Geronah ní Botswana.
Isẹ́ Òkè-òkun
àtúnṣeMoeng dúró fún Botswana ní ìpele àgbà ní àkókò ìdíje COSAFA Women's Championship ti ọdún 2021 àti Africa Women cup of nation qualification ti ọdún 2022 .
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedFBR