Liban Abdi Ali (tí a bí ní ọjọ́ Kàrún oṣù Kẹ̀wá ọdún 1988) jẹ́ agbábọ́ọù ọmọ orílẹ̀ ède Somalia. Ó fi ìgbà kan gbá fún ẹgbẹ́ Sheffield United ní England, fún Ferencváros ní Hungary, fún Olhanense ní Portugal, àti fún FK Haugesund ní Norway.

Liban Abdi
Liban Abdi.jpg
Abdi with Ferencváros
Personal information
OrúkọLiban Abdi Ali
Ọjọ́ ìbí5 Oṣù Kẹ̀wá 1988 (1988-10-05) (ọmọ ọdún 36)
Ibi ọjọ́ibíBurao, Somaliland
Ìga1.82m
Playing positionLeft winger
Youth career
Vålerenga
Skeid
2004–2007Sheffield United
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2007–2010Sheffield United0(0)
2008–2010Ferencváros (loan)17(3)
2008–2010Ferencváros II (loan)5(0)
2010–2012Ferencváros29(2)
2010–2012Ferencváros II14(7)
2012–2013Olhanense16(4)
2013–2014Académica de Coimbra11(0)
2014–2015Çaykur Rizespor13(1)
2015Levski Sofia (loan)9(2)
2016–2017Haugesund38(7)
2018Al-Ettifaq12(2)
Total164(28)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 17:40, 23 June 2019 (UTC).
† Appearances (Goals).

Wọ́n bi sí Somalia ṣùgbọ́n ó dàgbà sí Norway Ó sì ní ìwé ẹ̀rí pé ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀ ède Norway.[1] Wọ́n gbàá láyè láti gba bọ́ọ̀lù fún orílẹ̀ ède Somalia, àti fún orílẹ̀ èdè Norway.

Ìpìlẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Abdi ní Burao, Somaliland, Somalia, ní ọdún 1988. Ó dàgbà ní Oslo, Norway, níbi tí ó tí lọ ilé ìwé pámárì àti ṣẹ́kọ́ndírì. Ó tún gbé ní Stovner.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Farshchian, Aslân W.A. (31 August 2012). "Spiller fast i Portugal – ikke sett av Drillo" (in Norwegian). Verdens Gang. http://www.vg.no/sport/fotball/norsk/landslaget/artikkel.php?artid=10068265. Retrieved 19 October 2012.