Lijadu Sisters
Àwọn Lijadu Sisters ( Bibi ọjọ́ méjìlélógún oṣù Kẹ̀wá ọdún 1948), Taiwo ati Kehinde Lijadu (wọn kú ní ọjọ́ mẹsan oṣù mokanla ọdún 2019), àwọn méjèèjì je ìbejì tí wọn jọra gidi gan-an, wọn jẹ ọmọ Nigeria tí wọ́n jẹ àwọn olórin ìbejì Nigeria lati arin ọrùn ọdún 1960 títí di ọrùn ọdún 1980. Wọn se àṣeyọrí ni Naijiria Ati nipe wọn ní ipa pataki ni ilu Amerika Ati Yúróòpù. Nìkan tí wọ́n fi mọ àwọn nipe wọn jẹ ẹ̀yà àwọn ibeji pointer West Áfríkà,wọ́n máa dá orin Afro pẹlu jazz ati disco pò sí orin kan, láti orísun kan, ṣíṣú mọ òpin ọrùn ọdún 1980,wọn feyinti láti orin kíkọ . Wọn jẹ ìbátan sì akọrin olókìkí Fela Kuti.
Ìṣe
àtúnṣeÀwọn ìbejì na dàgbà ni Ibadan Naijiria,àwọn olorin yí jé awokose fún wọn nígbà tí wọ́n dàgbà Aretha Franklin, Victor Olaiya àti Miriam Makeba.ẹ̀rọ orin Lemmy Jackson je ìtọ́sọ́nà fún àwọn méjèèjì àti ní owun na ni wọ́n tọ́ka sí tó rán lọwọ ni àṣeyọrí.