Linda Ogugua (tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1978) je agbá-bọọọlu sínú agbọ̀n ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ó ń gba fún ẹgbẹ́ Women's basketball center. Ogugua lọ sí Fáṣítì ìlú California, ní orílè-èdè Amẹ́ríkà ódẹ̀ tún gbá bọọọlù pẹ̀lú the Nigeria women's national basketball team ní  2004 Summer Olympics.[1]

Ayé rẹ̀

àtúnṣe

A bí Ogugua sínú ìdílé Caroline Chinwe àti John Brown Ogugua ní ìpínlẹ̀ Anambra, ní orílè-èdè Nàìjíríà ni ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1978.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Àdàkọ:Cite Sports-Reference
  2. Linda Ogugua Archived 2007-05-12 at the Wayback Machine. Biola University profile