Little Walter
Marion Walter Jacobs (May 1, 1930 – February 15, 1968), tó gbajúmọ̀ bí i Little Walter, jẹ́ olórin, akọrin, àti akọ̀wé-orin blues. Ó jẹ́ ará ilẹl America tí ó kọrin lọ́nà tuntun bí i Jimi Hendrix.[1] Ìṣọwọ́korin rẹ̀ mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní ìrètí ohun tí orin blues máa dà lọ́jọ́ iwájú.[2]
Little Walter | |
---|---|
Fáìlì:Little Walter.jpg | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Marion Walter Jacobs |
Ọjọ́ìbí | Marksville, Louisiana, U.S. | Oṣù Kàrún 1, 1930
Ìbẹ̀rẹ̀ | Chicago, Illinois |
Aláìsí | February 15, 1968 Chicago, Illinois | (ọmọ ọdún 37)
Irú orin | |
Occupation(s) | Musician |
Instruments |
|
Years active | 1945–1968 |
Labels | |
Associated acts | |
Website | littlewalterfoundation.org |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Glover, Tony; Dirks, Scott; and Gaines, Ward (2002). Blues with a Feeling: The Little Walter Story. Routledge Press.
- ↑ Dahl, Bill Little Walter: Biography. Allmusic.com.