Lizzy Àńjọọ́rìn
Lizzy Àńjọọ́rìn tí orúkọ rẹ̀ gangan ń jẹ́ Elizabeth Ìbùkúnolúwa Àńjọọ́rìn (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù kẹrin) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìjọba ìbílẹ̀ Àgbádárìgì[1] ni ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Lizzy jẹ́ oníṣòwò bákan náà.
Aáyan rẹ̀ nínú iṣẹ́ tíátà
àtúnṣeLẹ́yìn tí ó di òṣèré sinimá àgbéléwò, ó ti ṣe olóòtú sinimá àgbéléwò mẹ́fà fúnra rẹ̀. Àwọn sinimá-àgbéléwò náà ni
- Tolani Gbarada;
- Gold;
- Iyawo Abuke;
- Kofo Tinubu;
- Kofo De First Lady;
- Owo Naira Bet.
Bákan náà, ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò kan bii;
- Owowunmi (2010);
- Arewa Ejo (2009);
- Ise Onise (2009).
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Elizabeth Ibukunoluwa( Lizzy Anjorin) - Home for Nollywood Movies". iBAKATV. Archived from the original on 2019-12-17. Retrieved 2019-12-17.