Lola Omolola (bíi ni ọjọ́ kìíní oṣù kẹjọ ọdún 1976) jẹ́ oníróyìn ọmọ Nàìjíríà, ó dá ẹgbẹ́ obìnrin FIN (Female IN) kalẹ̀ lórí Facebook, níbi tí àwọn obìnrin tí sọ àwọn ẹ̀dùn ọkàn wọn.[1]

Lola Omolola
Ọjọ́ìbí1976 (ọmọ ọdún 48–49)
Lagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian, American
Iṣẹ́Journalist, community engagement strategist

Ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Ó gboyè nínú broadcast journalism láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Columbia College ní Chicago.[2]

Iṣẹ́

àtúnṣe

Omolola jẹ́ oníróyìn, ó sì ti ṣe atọkun fún àwọn ètò ni ori telefisonu ni Nàìjíríà. Leyin ti o parí ẹ̀kọ́ rẹ ni ilé ẹ̀kọ́ gíga, ó si ṣẹ́ pelu agbegbe ìgbani-níyànjú ni Chicago níbi tí ó tí ń fun àwọn èèyàn ní ìmọ̀ràn nípa ọ̀rọ̀ ìlera wọn. Ó ní èrò ayélujára tìrẹ tí ó pè ní Spicebaby.com tí ó ti ń má fún àwọn èèyàn ní erongba tí wọn fi ṣe oúnjẹ. Ó dá ẹgbẹ́ obìnrin FIN (Female IN) kalẹ̀ lórí Facebook, níbi tí àwọn obìnrin tí sọ àwọn ẹ̀dùn ọkàn wọn, ẹgbẹ́ náà ní kọjá àwọn èèyàn mílíọ̀nù kan níbè.[1] Ó pàdé olùdásílè Facebook, wọn si jọ ṣọ̀rọ̀ lóri bíi àwọn obìnrin ṣe rí irànlọ́wọ́ gbà láti FIN.[3][4][5][6]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe