Lord Byron
George Gordon Byron, 6th Baron Byron, later George Gordon Noel, 6th Baron Byron, FRS (22 January 1788 – 19 April 1824), to gbajumo bi Lord Byron (Iba Bairon), je akoewi ara Britani ati eni asiwaju ninu Iseromansi. Ninu awon iwe Byron to gbajumo julo ni She Walks in Beauty, When We Two Parted, ati So, we'll go no more a roving, Childe Harold's Pilgrimage ati Don Juan. O je ikan ninu awon akoewi ara Britani to lokikijulo, won si unka awon iwe re titi doni.
The Right Honourable The Lord Byron FRS | |
---|---|
Portrait of Lord Byron by Thomas Phillips | |
Iṣẹ́ | Poet, politician |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | British |
Literary movement | Romanticism |
Notable works | Don Juan, Childe Harold's Pilgrimage |
Children | Ada Lovelace, Allegra Byron |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |