Louis 14k ilẹ̀ Fránsì
Louis Kẹrìnlá (Louis XIV'; 5 September 1638 – 1 September 1715; Luis Kerinla), to je mimo bi Oba Orun (Sun King (Faranse: le Roi Soleil), je Oba Fransi ati Navarre.[1] Ijoba re, lati 1643 de ojo iku re ni 1715, bere nigba to je omo odun merin, o si gba odun adorin le meji, osu meta ati ojo mejidinlogun, bee si ni ohun lo je oba to pe ju lori ite ni Europe ti a mo.[2]
Louis Kẹrìnlá Louis XIV | |
---|---|
![]() | |
Louis XIV (1638–1715), by Hyacinthe Rigaud (1701) | |
Reign | 3 October 1643 – 1 September 1715 ( ọdún 72 , ọjọ́ 110 ) |
Coronation | June 7, 1654 | (ọmọ ọdún 15)
Predecessor | Louis XIII |
Successor | Louis XV |
Regent | Anne of Austria (until 1651) |
Spouse | Maria Theresa of Spain Françoise d'Aubigné |
Issue | |
Louis, le Grand Dauphin Princess Anne Élisabeth Princess Marie Anne Princess Marie Thérèse Philippe Charles, Duke of Anjou Louis François, Duke of Anjou | |
Full name | |
Louis-Dieudonné de France | |
House | House of Bourbon |
Father | Louis XIII of France |
Mother | Anne of Austria |
Burial | Saint Denis Basilica, Saint-Denis, France |
Signature | ![]() |
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
ItokasiÀtúnṣe
- ↑ See List of Navarrese monarchs and their family tree.
- ↑ "Louis XIV". MSN Encarta. 2008. Archived from the original on 2009-11-01. Retrieved 2008-01-20.