Lucas Papademos
Lucas Papademos (Gíríkì: Λουκάς Παπαδήμος, pípè ní Gríikì: [luˈkas papaˈðimos], Loukas Papadimos; abi ni Athens ni October 11, 1947) je Griiki asetookowo ati lowolowo Alakoso Agba orile-ede Griisi. Teletele, o ti je Gomina Banki Griisi lati 1994 de 2002 ati Tgbakeji Aare Banki Aringbangan Yuropu lati 2002 de 2010. O je ojogbon aseabewo fun eto igbooro ni Kennedy School of Government ni Yunifasiti Harvard ati Elegbe Agba ni Center for Financial Studies ni Yunifasiti Frankfurt.[1]
Lucas Papademos Λουκάς Παπαδήμος | |
---|---|
Prime Minister of Greece | |
In office 11 November 2011 – 16 May 2012 | |
Ààrẹ | Karolos Papoulias |
Deputy | Theodoros Pangalos |
Asíwájú | George Papandreou |
Arọ́pò | Panagiotis Pikrammenos |
Vice President of European Central Bank | |
In office 31 May 2002 – 31 May 2010 | |
Ààrẹ | Wim Duisenberg Jean-Claude Trichet |
Asíwájú | Christian Noyer |
Arọ́pò | Vítor Constâncio |
Governor of the Bank of Greece | |
In office 26 October 1994 – 31 May 2002 | |
Deputy | Panagiotis Thomopoulos |
Asíwájú | Ioannis Boutos |
Arọ́pò | Nikolaos Garganas |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kẹ̀wá 1947 Athens, Greece |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Shanna Ingram |
Alma mater | Massachusetts Institute of Technology |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣeWikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Lucas Papademos |