Lucie Memba
Lucie Memba Bos je osere ati aberejade omo ilu Cameroon ti won bi ni odun 1987, oti kopa ninu awon ere ede Faranse ati ede geesi[1] Won ye si pelu ami eye osere iwaju ti o dara ju ni Cinema titi cameroon fun awon esere elede Faranse ni Cameroon Movies Merit Award (CMMA) titi odun 2013.[2] O ko ipa ninu ere Nollywood ti akori re Pink Poison pelu Jim Iyke[3] ati Far pelu Dakore Akande[4]Ni odun 2014 o se ifi lole L.M.B production, eleyi ti o so ni oruko e. O se agbejade ere cameroon ti akori e je Paradise, ni odun yi na ose agbejade ere LA Patrie D'Abord, ere ogun ti won fi ranti awon ajagun Cameroon[5] Ni odun 2017, won yan fun osere birin ile Cameroon ti o dara julo fun ami eye Trophees Francophes Du Cinema, fun ipa re ninu ere La Patrie D'abord[6]
Lucie Memba | |
---|---|
Lucie Memba | |
Ọjọ́ìbí | 1987 (ọmọ ọdún 36–37) Dschang, West Region Cameroon |
Orílẹ̀-èdè | Cameroonian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Cameroonian (1987–present) |
Iṣẹ́ | Asejagbejade ere, Osere |
Ìgbà iṣẹ́ | 1999–titi di isinyi |
Igbesi aye ibẹrẹ
àtúnṣeWon bi Lucie ni Dschang West Region titi Cameroon osi dagba si Bafoussam ibi ti oti bere ise modeli lehin na ni obere ise osere. O ga oye-oye ni Baccalauréat philosophique owa ko lo si ilu Douala fun awon ise imi.[7] Ko si alaye llori ojo ibi e, awon kan gba pe odun 1987 ni won bi.
Ise
àtúnṣeLucie koko jade ninu ere "Emoin A Seduire" ni odun 1999 nigba ti Cinema titi Cameroon sese n dagba[8] O di gbajumo ni odun 2008 lehin igbano ni o gba ami eye osere ti o dara julo fun CMMA Cameroon Movies Merit Award ni odun 2013. O se agbekale ile ise titi eh no, eyi ti o pe ni Lucie Memba Bos (LMB). Ohun lo gbe ere Paradise jade, ise e ninu La patrie d’abord, je eyi ti oje gbajumo fun gege bi alagbejade ise na, fiimu na ni won fi pan awon ologun Cameroon le, ni odun 2014 otun bawon se abejade ere "Ntah Napi" eleyi ti ogba ami eye fun ere faranse ti o dara julo lowo Ecrans Noirs[9] Owa lara awon osere ilu Cameroon ti ise won ti di mimo lati ajo asa ati ise ti ilu Cameroon, owa lara awon ti o pade Ama Tutu Muna eyi ti o se abewo si ibi ti won ti se ere Pink Poison ni Buea[10]
Ni odun 2016 won ni ohun ni osere ilu Cameroon ti on dan ju lati owo Le Film Camerounais[11] Otun je gbajumo fun ere Fast Life pelu osere okurin Thomas Nguijol.[12] O sise pelu Tribe Africa Media lati fifehan si awon Afin ni ilu Cameroon[13]Àdàkọ:Cquote
Yato si iṣẹ rẹ ni fiimu, ni ọdun 2008, Guinness Cameroon gba si ise gẹgẹbi oluṣowo titaja
Igbesi aye ara ẹni
àtúnṣeNi osu kesan odun 2017, Lucie pade pẹlu akọọlẹ bọọlu afẹsẹgba Ilu Cameroon Samuel Eto'o ni Douala [14]
Awon Asayan Ere
àtúnṣeOdun 2011 si 2017
àtúnṣe- Deiting the 6th
- Ntah napi de ousmane stéphane et sergio marcellos
- Paradise
- W.a.k.a
- First country
- La maladie
- Mission secrete
- Far With Dakore Akande
- Pink Poison with Jim Iyke
- Le Blanc D’Eyanga
- a Partrie D’abord
- Fast Life
Odun 2009
àtúnṣe- Sweet home de ghislain amougou
- Passion. Com de serge kendjo
Odun 2008
àtúnṣe- Série Paradis D’ousmane Stéphane
- Série Le Monde De Loïc, De Raphaël Matouke
- Virus Squad
Awards ati ti idanimọ
àtúnṣeOdun | Eye | Ẹka | Olugba | Esi |
---|---|---|---|---|
2017 | TROPHEES FRANCOPHONES DU CINEMA | Ti o dara ju oṣere | Funrararẹ| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |
Ọdun 2013 | Eye Awọn ere Fiimu Ilu Kamẹrin (CMMA) | Ti o dara ju oṣere | Funrararẹ| Gbàá | |
Ọdun 2014 | Encrain Noir | Fiimu Faranse ti o dara julọ | Iṣẹ rẹ| Gbàá |
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ "Nigercultures - Lucie Memba". nigercultures.net. Archived from the original on 20 September 2017. Retrieved 22 September 2017.
- ↑ "QUI EST LUCIE MEMBA BOS ?" (in french). culturebene.com. 1 August 2016. http://www.culturebene.com/22506-qui-est-lucie-memba-bos.html. Retrieved 18 September 2017.
- ↑ Kanjo, Ernest. "TIPTOPSTARS - ONLINE MAGAZINE Array Pink Poison Reloaded: Culture minister visits actors on location". www.tiptopstars.com. Retrieved 22 September 2017.
- ↑ "CAMER FILM ALERT: THE "FAR" MOVIE PREMIERE THIS WEEKEND - I Rep Camer". irepcamer.com. 29 October 2014. Archived from the original on 20 September 2017. Retrieved 22 September 2017.
- ↑ "Qui est Lucie MEMBA BOS ? - Culturebene". culturebene.com. 1 August 2016. Retrieved 22 September 2017.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2017-10-16. Retrieved 2020-10-18.
- ↑ "Qui est Lucie MEMBA BOS ? - Culturebene". culturebene.com. 1 August 2016. Retrieved 22 September 2017.
- ↑ "Lucie Memba Bos: Passionnée du 7ème art – Tendancespeoplemag". tendancespeoplemag.com. Retrieved 22 September 2017.
- ↑ "Lucie Memba to star alongside Nollywood actor Zack Orji in new film – Dcoded TV". dcodedtv.com. Retrieved 22 September 2017.
- ↑ Kanjo, Ernest. "TIPTOPSTARS - ONLINE MAGAZINE Array Pink Poison Reloaded: Culture minister visits actors on location". www.tiptopstars.com. Retrieved 22 September 2017.
- ↑ "PEOPLE : Lucie Memba Bos, actrice la plus glamour 2016". lefilmcamerounais.com. 9 August 2016. Retrieved 22 September 2017.
- ↑ http://www.allocine.fr/article/fichearticle_gen_carticle=18634466.html
- ↑ "Today is world Albino day,See how Memba Lucie,Laura Dave,Alain Ngann and more celebrates this day(photos)⬇⬇⬇". wordpress.com. 13 June 2017. Archived from the original on 20 September 2017. Retrieved 22 September 2017.
- ↑ https://dcodedtv.com/lucie-memba-gushes-over-samuel-etoo/