Lucky Igbinedion
Olóṣèlú
Lucky Nosakhare Igbinedion ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Karùn ún, ọdún 1957, jẹ́ ọmọ bíbí àti gómìnà Ìpínlẹ̀ Ẹdó nígbà kan rí lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP, ní ọdún 1999 sí ọdún 2007.[1].
Lucky Nosakhare Igbinedion | |
---|---|
Governor of Edo State | |
In office 29 May 1999 – 29 May 2007 | |
Asíwájú | Anthony Onyearugbulem |
Arọ́pò | Oserheimen Osunbor |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 13 May 1957 |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Mrs Eki Igbinedion |
Àwọn ọmọ | Dr Mrs Ehi Oni (nee Igbinedion), Mr Nosa Igbinedion Jr, Mr Osaretin Igbinedion, Ms Osasu Igbinedion, Mrs Zena Enaholo (nee Igbinedion), Ms Aize Ibginedion |
Education | MBA |
Alma mater | Jackson State University, Mississippi, US |
Website | http://www.luckyigbinedion.co.za/ |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2018-07-24. Retrieved 2020-05-03.