Ludwig van Beethoven (pípè /ˈluːdvɪɡ vɑːn ˈbeɪtoʊvən/ (U.S.)tabi /ˈlʊdvɪɡ væn ˈbeɪt.hoʊvən/ (UK); Jẹ́mánì: [ˈluːtvɪç fan ˈbeːt.hoːfn̩]  ( listen); iribomi ni 17 December 1770[1] – 26 March 1827) je alakopo orin ati oniduuru ara ile Jemani. Ohun ni eni pataki ju nigba iyipada larin igba orin Klasika ati Romantik ninu orin klasika Europe, be sini o je alakopo orin togbajulo ati tonipajulo.

A portrait by Joseph Karl Stieler, 1820


Itokasi àtúnṣe

  1. Beethoven was baptised on 17 December. His date of birth was often, in the past, given as 16 December, however this is not known with certainty; his family celebrated his birthday on that date, but there is no documentary evidence that his birth was actually on 16 December.