Luis Alberto Riart (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún, oṣù kẹfà, ọdún 1880[1], ó sì kú ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1953) jẹ́ àgbà òṣẹ̀lú orílẹ̀-èdè Paraguay àti Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Paraguay láti ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹta ọdún 1924 sí ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹjọ ọdún 1924.

Luis Alberto Riart
31st President of Paraguay
In office
March 17, 1924 – August 15, 1924
AsíwájúEligio Ayala
Arọ́pòEligio Ayala
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíJune 21, 1880
Villa Florida
AláìsíOctober 1, 1953 (aged 73)
Asunción
Ọmọorílẹ̀-èdèParaguayan
Ẹgbẹ́ olóṣèlúLiberal

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe