Luisa Diogo
Luísa Dias Diogo (ojoibi April 11, 1958) je Alakoso Agba orile-ede Mozambique lati February 2004 titi di January 2010. O dipo Pascoal Mocumbi, to ti je Alakoso Agba fun odun mesan. Ki o to di Alakoso Agba, o je Alakoso Iseto ati Isuna, ipo to dimu titi di February 2005.[2]
Luisa Diogo | |
---|---|
Diogo at the World Economic Forum Annual Meeting 2009. | |
Alakoso Agba ile Mozambique | |
In office 17 February 2004 – 16 January 2010 | |
Ààrẹ | Joaquim Chissano Armando Guebuza |
Asíwájú | Pascoal Mocumbi |
Arọ́pò | Aires Ali |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kẹrin 1958 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Liberation Front |
Alma mater | Eduardo Mondlane University School of Oriental and African Studies |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ http://web.archive.org/web/20070930155152/http://www.um.dk/NR/rdonlyres/C0FC7516-C5A4-4BBB-A40D-5F56C5142300/0/CVLuisaDiogo.doc
- ↑ Mateus Chale, "Guebuza names cabinet to fight poverty", Reuters (IOL), February 4, 2005.