Àwọn ẹ̀yà yìí wà ní orílẹ̀ èdè Congo, Zambia àti Angola, èdè wọn sì jẹ́ ẹ̀yà ti Bantu. Wọ́n dín díẹ̀ ní ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án wọ́n sì múlé gbe ẹ̀yà Yaka, Suku, Chokwe abbl.[1] A rí àgbẹ̀, apẹja àti onísòwò tààrà ni orílẹ̀ èdè yìí. Mwaat Yaav ni ọba wọn, àwọn ìjòyè náà sì wà. Baálẹ̀ kọ̀ọ̀kan náà sì sà ṣùgbọ́n ìsákọ́lẹ̀ pọn dandan. Wọ́n máa ń dífá alágbọ̀n ṣùgbọ́n wọ́n gbàgbọ́ nínú nzambi.

Àwọn ènìyàn Lúndà ní orílẹ̀-èdè Congo

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Angola - Culture, History, & People". Encyclopedia Britannica. 2010-02-05. Retrieved 2020-07-03.