Lydia Akoth
Lydia Akoth jẹ̀ agbabọọlu lobinrin orilẹ ede kenya ti a bini 22, óṣu september ni ọdun 1994. Agbabọọlu naa ṣere fun Thika Queens FC gẹgẹbi Midfielder[1][2][3].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 22 Oṣù Kẹ̀sán 1994 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Kisumu, Kenya | ||
Playing position | Midfielder | ||
Club information | |||
Current club | Thika Queens FC | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Thika Queens FC | |||
National team | |||
Kenya women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Lydia kopa ninu Nations Cup awọn obinrin ilẹ afirica ni ọdun 2016[4].